Udo Oluchi Ibeji jẹ olóṣèlú ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà. O jẹ ọmọ ile-igbimọ aṣofin tẹlẹ, nibiti o ti ṣoju ẹkun idibo àpapọ̀ Ikwuano -Umuahia ti Ìpínlè Abia . [1] [2] [3]