Ufuoma Isioro Onobrakpeya (tí wọ́n bí ní ọdún 1971), jẹ́ ayàwòrán, aṣe-ọ̀dà a ̀ti olùkọ iṣẹ́-ọnà ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà. Ufuoma jáde láti inú ìdílé àwọn oníṣẹ́-ọnà, torí bàbá-bàbá rẹ̀ tí í ṣe Omonedo Onobrakpeya jẹ́ agbẹ́gilére. Ìgbà tí òun náà ń dá̀gbà, ó kọ́ṣẹ́ lọ́wọ́ bàbá rẹ̀, ìyẹn Bruce Onobrakpeya fún bí i ogún ọdún.[1][2][3]

Ìgbésị Ayé

àtúnṣe

A bi Ufuoma Onobrakpeya ní ọjọ́ kọkànlélógún oṣù kejì, ọdún 1971 ní ìpínlẹ̀ èkó, ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Bàbá a rẹ̀ ni ayàwòrán Bruce Onobrakpeya. O kẹ́kọ̀ó gboyè ní ilé ẹ̀kọ́ gíga ti Benin ni ọdún 1995,

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Ekeh, Peter Palmer (2005) (in en). Studies in Urhobo Culture. Urhobo Historical Society. ISBN 978-978-067-769-5. https://books.google.com/books?id=jjeNIESBArkC&q=%22Ufuoma+Onobrakpeya%22+-wikipedia&pg=PA662. 
  2. (in en) Contemporary Issues in Nigerian Art: Its History and Education. Portion Consult Publications. 2006. ISBN 978-978-077-026-6. https://books.google.com/books?id=QpFJAQAAIAAJ&q=%22Ufuoma+Onobrakpeya%22+-wikipedia. 
  3. "Printmakers honour Onobrakpeya". Latest Nigeria News, Nigerian Newspapers, Politics (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-01-20. Retrieved 2020-07-02.