Uganda Green Party
Uganda Green Party(ẹgbẹ́ òsèlú aláwọ̀ ewé ti Uganda) jẹ́ ẹgbẹ́ olóṣèlú aláwò ewé kan tí ó wà ní orílẹ̀ èdè Uganda. Ẹgbẹ́ náà sọ pé ète wọn ni láti ṣa ipá wọn nínu àyíká àti agbègbè wá ní àlàáfíà, kìí ṣe láti ṣe òsèlú. Ète rẹ̀ ni láti dáàbò bo àdúgbò àti àwọn tí olùgbé ibẹ̀.