Ugochi Opara jẹ àkọṣẹmọṣẹ agbàbọọlu lobinrin orilẹ ede naigiria ti a bini 27, óṣu May ni ọdun 1976. Arabinrin na ṣere gẹgẹbi goalkeeper fun team awọn obinrin naigiria ti national lori bọọlu[1][2].

Ugochi Opara
Personal information
Ọjọ́ ìbí27 Oṣù Kàrún 1976 (1976-05-27) (ọmọ ọdún 48)
Playing positionGoalkeeper
National team
Nigeria women's national football team0(0)
† Appearances (Goals).
‡ National team caps and goals correct as of 20 September 2003 (before the 2003 FIFA Women's World Cup)

Àṣeyọri

àtúnṣe
  • Ugochi wa lara team Cup FIFA awọn obinrin agbaye ni ọdun 1995 ati 2003[3].

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://www.eurosport.com/football/ugochi-opara_prs414752/person.shtml
  2. https://ng.soccerway.com/players/ugochi-opara/291425/
  3. https://peoplepill.com/people/ugochi-opara