Uju Okeke
Obianuju Blessing Okeke tí ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bíi Uju Okeke jẹ́ òṣèré ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí ó gbajúmọ̀ fún ipa tí ó kó nínú eré Mission to Nowhere àti The Barrister. Wọ́n bíi Obianuju sí ìpínlè Anambra. Ó gboyè nínú ìmò eré orí ìtàgé láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Yunifásítì Nnamdi Azikiwe.[1] Ní ọdún 2012, ó fẹ́ Melekh, wọ́n sí ṣe ìgbéyàwó wọn ní ilé ìjọsìn ti Saint Barth Anglican Church ní ìpínlẹ̀ Èkó.[2]
Uju Okeke | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Obianuju Blessing Okeke Lagos, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Nnamdi Azikiwe University |
Iṣẹ́ | Nollywood Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 2004–present |
Olólùfẹ́ | Melekh |
Iṣẹ́
àtúnṣeNí ọdún 2006, Okeke kó ipa ọmọ ọ̀dọ̀ nínú eré Mission to Nowhere èyí tí Teco Benson gbé kalẹ̀. Ní ọdún 2017, ó gbà àmì ẹ̀yẹ Next Upcoming Artist láti ọ̀dọ̀ Africa Movie Academy Awards fún ipa tí ó kó nínú eré náà.[3]
Àṣàyàn àwọn eré tí ó tí ṣe
àtúnṣeỌdún | Àkọ́lé | Ipa tí ó kó |
---|---|---|
2006 | The Barrister | Actress |
2006 | Mission to No Where | Actress: Maid |
Àwọn Ìtọ́kàsi
àtúnṣe- ↑ "Honour for Uju Okeke from her alma mater". The Guardian. Archived from the original on 15 November 2020. Retrieved 12 October 2020.
- ↑ "Nollywood actress Uju Okeke ties the knot". thenigerianvoice. Retrieved 12 October 2020.
- ↑ "Honour for Uju Okeke from her alma mater". The Guardian. Archived from the original on 15 November 2020. Retrieved 12 October 2020.