Umaru Abdullahi
Umaru Abdullahi (born November 30, 1939) jẹ́ adájọ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti Ààrẹ tẹ́lẹ̀ ti àwọn ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn ní Nàìjíríà.[1]
Umaru Abdullahi | |
---|---|
President of the Nigerian courts of appeals | |
In office 1999–2009 | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 30 Oṣù Kọkànlá 1939 |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Non partisian |
Íse rẹ gẹgẹ bí olófin
àtúnṣeJustice Umaru was Call to the bar ni ọdún 1968 a sì Yàn gẹgẹ bí ọkan lára àwọn alága Nigerian courts of appeal ni ọdún 1983 gẹgẹ bí adájọ .[2][3] Ni odún 1987, a gbè ló sì ilú Kastina State láti je olùrànlọwọ to dá ilẹ idajo ìpínlè ni ọdún mẹta kọja,a fí je oyè àrè ile ìdájọ ko témi lọrùn, A Yàn gẹgẹ bí President of the Nigerian courts of appeals, ipò tí o di mú fún ọdún mẹwa láti 1999 Títí dé 2009 a sì ṣí ní ipò fún Ayo Salami a tí kò ìwé nípa ìgbé ayé rẹ tí àkòrí rẹ je about , 'Once Upon Umaru' by Ibe Ikwechegh. Justice Abdullahi o jẹ oye é ni ti ọ niyi of Walin Hausa .[4][5]
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Fasua, Tope (2007-12-18). "Nigerian News, Articles, Current Events, & Musings". NigerianMuse. Archived from the original on 2022-02-04. Retrieved 2022-02-08.
- ↑ "Justice Umaru Abdullahi's Court of Appeasement, Corruption and Confusion". Sahara Reporters. Retrieved 29 April 2015.
- ↑ "Court of appeal, Nigeria". courtofappeal.com. Archived from the original on 29 April 2015. Retrieved 29 April 2015.
- ↑ "CJN Versus President, Court Of Appeal: Hon. Justice Umaru Abdullahi Report; Who Lied On Oath?". Sahara Reporters. Retrieved 29 April 2015.
- ↑ "Justice Umaru Abdullahi - DailyPost Nigeria". DailyPost Nigeria. Retrieved 29 April 2015.