Ummi Ibrahim
Ummi Ibrahim jẹ́ òṣèrébìrin Kannywood (An Hausa Language Cinema) tó di olókìkí nínú fíìmù Jinsi níbi tí ó ti ní orúkọ rẹ̀ ní Zeezee.[1][2]
Ummi Ibrahim | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 1987 (ọmọ ọdún 36–37) Borno State |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Iṣẹ́ | Kannywood actress, musician, business woman |
Ìgbà iṣẹ́ | 2006 – present |
Iṣẹ́ Rẹ̀
àtúnṣeÀríyànjiyàn wà nípa òṣèré náà ní ilé-iṣẹ́ náà bí ó ṣe sọ pé òun lòún ga jùlọ. Èyí fa ifarapa láàrín àwọn ẹlẹ́gbẹ́ rẹ̀ láti ìgbà tí wọ́n ti ríi kẹ́hìn ní Kannywood ní ọdún 2006. [3]
Àwọn Fíìmù Rẹ̀
àtúnṣe- Jinsi[2]
- Flag of Love
- Yan uwa
- Gambiza
- Gender
Àwọn Ìtọ́ka Sí
àtúnṣe- ↑ Online, Tribune (20 September 2017). "6 High-flying Kannywood actresses". Tribune Online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 6 August 2022.
- ↑ 2.0 2.1 "Zee-Zee: The rise and rise of Jinsi queen". www.thenigerianvoice.com. Retrieved 8 August 2022.
- ↑ Lere, Mohammed (29 April 2017). "Supremacy Tussle in Kannywood: Umma Shehu blasts Ummi ZeeZee, says she's a small fry". Premium Times Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 6 August 2022.