Yunifásítì ìlú Benin

Yunifasiti gbogbogbo ni Nigeria
(Àtúnjúwe láti University of Benin (Nigeria))

Yunifásítì ìlú Benin jé yunifásítì ìjoba ní ìlú benin, ìpínlè Edo ni orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Adá kalè ní ojo kíní, osù keje, odun 1970 [1]

University of Benin front view
Yunifásítì ìlú Benin
àtúnṣe



  1. "University of Benin, Nigeria". Top Universities. 2020-06-09. Retrieved 2022-03-03.