University of Johannesburg
Àdàkọ:Use South African English
University of Johannesburg | |
---|---|
Àdàkọ:Nativename | |
University of Johannesburg brand logo | |
Motto | Diens Deur Kennis (Afrikaans) |
Motto in English | Service Through Knowledge |
Established | Oṣù Kínní 1, 2005 |
Type | Public university |
Chairman | Mike Solomon Teke[1] |
Chancellor | Phumzile Mlambo-Ngcuka[1] |
Vice-Chancellor | Letlhokwa George Mpedi |
Academic staff | 1,276[2] |
Students | 50,786[3] |
Undergraduates | 41,628[4] |
Postgraduates | 9,080[5] |
Location | Johannesburg, Gauteng, South Africa 26°11′00″S 27°59′56″E / 26.1834°S 27.9988°E |
Campus | Auckland Park Kingsway (APK) Auckland Park Bunting Road (APB) Doornfontein (DFC) Soweto (SWC) |
Former names | Randse Afrikaanse Universiteit (Rand Afrikaans University) (1967–2004) |
Colours | Orange Yellow White |
Nickname | UJ |
Mascot | University of Johannesburg Hoopoe "Hoepie"[6] |
Website | uj.ac.za |
University of Johannesburg, tí a tún mọ̀ sí UJ, jẹ́ Public Uiversity (Ilé-ẹ̀kọ́ gíga ìjọba) tí ó wà ní Johannesburg, South Africa. Wọ́n dá ilé ẹ̀kọ́ gíga náà sílè ní January, lalátàrí àpapò Rand Afrikaans University (RAU), Technikon Witwatersrand(TWR), àti àwọn ọgbà Soweto àti East Rand Vista University.[7] kí wọ́n tó ṣe àpapọ̀ òun àti àwọn ọgbà aveyton and Soweto tí ilé ẹ̀kọ́ gíga Vista University ni wọ́n tí kọ́ parapò di RAU. Látàrí ìparapò yìí, àwọn tí wọ́n tí jáde ní ilé ẹ̀kọ́ náà máa ń sábà pèé ní RAU.
Iléẹ̀kọ́ yìí wà lára àwọn Comprehensive universities[7] i tó dá jù lọ ní orílè èdè South Africa nínú àwọn ilé ẹ̀kọ́ gíga ìjọba 26 tí ó wà ní orílè èdè náà. UJ ní àwọn ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ tí òunka wọn tó 50 000, 3000 tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ nínu àwọn akẹ́kọ̀ọ́ yìí jẹ́ àwọn ọmọ láti òkè òkun láti orílé èdè oríṣiríṣi tí òunka wọn jẹ́ 80.[8]
- ↑ 1.0 1.1 "UJ Governance". www.uj.ac.za (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 19 October 2017.
- ↑ "UJ Key Statistics". University of Johannesburg (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì).
- ↑ "UJ Key Statistics". University of Johannesburg (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 6 June 2024.
- ↑ "UJ Key Statistics". University of Johannesburg (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 6 June 2024.
- ↑ "UJ Key Statistics". University of Johannesburg (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 6 June 2024.
- ↑ "UJ’s mascot Hoepie graduates!". University of Johannesburg News. Retrieved 6 June 2024.
- ↑ 7.0 7.1 "Full List of NRF-rated Researchers" (PDF). University of Johannesburg. Archived from the original (PDF) on 11 April 2019. Retrieved 18 September 2017. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "About Us". University of Johannesburg.