Unoma Ndili Okorafor jẹ́ onímọ̀ ẹ̀rọ kọ̀m̀pútà àti oníṣòwò. Okorafor ṣe ìdásílẹ̀ Working to Advance African Women ní ọdún 2007,[1] WAAW is a 501(c) not-for-profit which promotes STEM education to African women.[1] èyí tó jẹ́ ilé-iṣẹ́ àìlérè lórí tó ń ṣe ìrànlọ́wọ́ fún ètò-ẹ̀kọ́ àwọn obìnrin nínú ìmọ̀ ẹ̀rọ, ṣáyẹ́ǹsì àti ìṣirò.[2] They have over one hundred volunteer university fellows and reach several thousand girls a year.[2] Òun ni adarí àgbà ní Herbal Goodness àti Fairview Data Technologies.[3] Ó jẹ́ ọmọ karùn-ún ti Frank Nwachukwu Ndili, ẹni tó jẹ́ ọmọ Nàìjíríà àkọ́kọ́ tó máa ní ìmọ̀ nípa anuclear physics, tó sì tún jẹ́ gíwá keje ti University of Nigeria, Nsukka.

Unoma Ndili Okorafor
Okorafor speaks at the Gem Tech Awards 2016
Ilé-ẹ̀kọ́Working to Advance African Women
Ibi ẹ̀kọ́University of Lagos

Rice University

Texas A&M University
Doctoral advisorDeepa Kundur

Àwọn ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. 1.0 1.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :02
  2. 2.0 2.1 Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named :03
  3. ""Meet the founder of Working to Advance African Women (WAAW), Dr Unoma Okorafor" – The TOWN icon | WAAW Foundation". waawfoundation.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2018-07-11. Retrieved 2018-07-10.