Uru Eke /θj/ (tí wọ́n bí ní October 11, 1979) jẹ́ òṣèrèbìnrin ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà àti aṣàgbéjáde fíìmù àgbéléwò. Ó gbajúmọ̀ fún fíìmù rẹ̀ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ "Remember Me".Ó kópa gẹ́gẹ́ bí i ẹ̀dá-ìtàn Obi nínú àwọn fíìmù orí èrọ-amóhùnmáwòrán lórí Ndani TV, bí i Rumour Has It. Last Flight to Abuja, àti fíìmù ẹléẹ̀kejì tó ṣàgbéjáde, tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ For Old Times' Sake.[1] Òṣèrébìnrin náà tó fìgbà kan jẹ́ onímọ̀ ẹ̀rọ kí ó tó darapọ̀ mọ́ iṣẹ́ fíìmù ṣì máa ń wá àyè láti ṣe iṣẹ́ ìmọ̀ ẹ̀rọ[2].

Uru Eke
Ọjọ́ìbí11 October 1979 (1979-10-11) (ọmọ ọdún 45)
Newham, East London
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ẹ̀kọ́Business Information Technology, University of Greenwich
Iṣẹ́Actress and film producer
Gbajúmọ̀ fúnHer role as Obi in Ndani TV
Notable workLast Flight to Abuja

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ àti ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀

àtúnṣe

Eke wá láti ìràn Mbaise region, ní Ipinle Imo, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, àmọ́ ìlú Newham, East London ní United Kingdom ni wọ́n bí i sí[3]. Ilé-ìwé alákọ̀óbẹ̀rẹ̀ Galleywall Infants School, ní London ló lọ, kí ó tó wá sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, níbi tí ó ti lọ sí Gideon Comprehensive High School fún ẹ̀kọ́ girama. Láti tèíwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀, ó padà lọ sí ìlú London, ó sì lọ sí Lewisham College, kí ó ṣẹ̀ tó lọ University of Greenwich, níbi tó ti kọ́ ẹ̀kọ́ nípa Business Information Technology.[3][4]

Àtọ̀jọ àwọn fíìmù rẹ̀

àtúnṣe

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "I'm not a stupid romantic - Uru Eke - Vanguard News". vanguardngr.com. 1 June 2013. Retrieved 8 October 2016. 
  2. "I'm not a stupid romantic - Uru Eke". Vanguard News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2013-05-31. Retrieved 2021-02-27. 
  3. 3.0 3.1 Okwara, Vanessa (17 April 2016). "Nollywood Actress Uru Eke: I’m From Mbaise In Imo State But Was Born In London UK". Sunday Telegraph. www.naijagists.com. Retrieved 8 October 2016. 
  4. "Uru Eke". Alumni | University of Greenwich (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-20. 
  5. Duthiers, Vladimir (2012-09-04). "'Last flight to Abuja': Nollywood thriller campaigns for safer skies". CNN (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-07-16. 
  6. "Nollywood movie review: Being Mrs. Elliot". Premium Times. Onyinye Muomah. Retrieved 28 September 2014. 
  7. "BEING MRS ELLIOT / OMONI OBOLI, MAJID MICHEL". 9FLIX. 9flix. Archived from the original on 13 June 2014. Retrieved 20 September 2014.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  8. "'Being Mrs Elliott' Watch movie review by Adenike Adebayo". Pulse Nigeria. Chidumga Izuzu. Archived from the original on 28 May 2015. Retrieved 28 May 2015. 
  9. "Cinema Review: 'Remember Me' is Uru Eke’s remarkable debut attempt" (in en-GB). http://thenet.ng/2016/03/cinema-review-remember-me-is-uru-ekes-remarkable-debut-attempt/.