Uti Nwachukwu (tí wọ́n bí ní 3 August 1982) jẹ́ òṣèrékùnrin àti olóòtú ètò ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ Jara. Ọ́ wá láti Ndokwa, Aboh Kingdom, agbègbè ìjọba ìbílẹ̀ Ndokwa East, Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà, ní Nàìjíríà.[1][2]

Uti Nwachukwu
Ọjọ́ìbíUti Nwachukwu Emeka
3 Oṣù Kẹjọ 1982 (1982-08-03) (ọmọ ọdún 42)
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaBenson Idahosa University University of Nigeria, Nsukka
Iṣẹ́Tv personality, actor
Gbajúmọ̀ fúnWinner of Big Brother Africa 5
Awards2012 GIAMA "Best New Actor"

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀

àtúnṣe

Uti wá láti ìdílé elénìyàn mẹ́fà. Ìpínlẹ̀ Delta ni ó dàgbà sí, ní Ughelli lójú òpópónà Uloho. Ilé-ìwé Igbenedion Education Center ló lọ láti ọdún 1993 wọ 1999. Ó gboyè ẹ̀kọ́ nínú ìmọ̀ computer science ní University of Nigeria in Nsukka àti oyè bachelor's degree láti Benson Idahosa University ní Benin City.[3]

Àtòjọ àwọn fíìmù rẹ̀

àtúnṣe

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Uti Nwachukwu". Africa Magic - Uti Nwachukwu (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-03-18. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  2. "Viral video: Actor Uti Nwachukwu faults father who cut son's dreadlocks". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-04-24. Retrieved 2022-07-18. 
  3. "Uti Nwachukwu biography, net worth, age, family, contact & picture". www.manpower.com.ng. Retrieved 2022-07-19.