Uwazurike Patrick
Uwazurike Chudi Patrick jẹ́ olóṣèlú ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà . Ó sìn gẹ́gẹ́ bí ọmọ ẹgbẹ́ tó ń ṣoju Isiala Mbano / Okigwe / Onuimoni ilé ìgbìmò asofin . Wọ́n yàn án sí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin orílẹ̀-èdè, láti ọdún 2011 sí 2012, lábẹ́ ìpele ẹgbẹ́ òṣèlú Peoples Democratic Party (PDP). [1]
Uwazurike Patrick | |
---|---|
Member of the House of Representatives of Nigeria from Imo | |
In office 2011-2012 | |
Constituency | Isiala Mbano/Okigwe/Onuimo |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | Peoples Democratic Party |