Uzee Usman
Uzee Usman | |
---|---|
Uzee Usman on set for Taurarin Zamani | |
Ọjọ́ìbí | Uzee Usman Adeyemi 11 Oṣù Kọkànlá 1986 Kaduna, Kaduna State, Nigeria |
Iléẹ̀kọ́ gíga | |
Iṣẹ́ | film producer, actor, television presenter |
Ìgbà iṣẹ́ | 2003–present |
Uzee Usman Adéyẹmí tí wọ́n bí ní ọjó Kọkànlá oṣù Kọkànlá ọdún 1986, jẹ́ Òṣèré orí-ìtàgé àti sinimá, olùgbéré-jáde, adarí eré, òun ni ó gbé eré tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Oga Abuja jáde. [1]Ó jẹ́ òṣèré tí ó ní agbáea láti máa kópa nínú agbo Nollywood àti Kanywood lápapọ̀ láì fara gbọ́n ibìkan. Akitiyan yí sì ti fun ní ànfaní láti gba àwọn Amì-ẹ̀yẹ iríṣiríṣi bíi amì-ẹ̀yẹ Young Entrepreneur of the Year níọdún 2016 níbi ayẹyẹ "National Heritage Award".[2][3]
Ìgbà èwe rẹ̀
àtúnṣeUsman ni ó jẹ́ ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Kwara, àmọ́ wọ́n tọ dàgbà ní Ìpínlẹ̀ Kàdúná, Ó ti kàwé gboyè nínú ẹ̀kọ́ ìmò nípa ìṣèlú àti ìmó̀ nípa èdè Gẹ̀ẹ́sì ní ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásitì Àbújá àti Yunifásitì Jos ṣáájú kí ó tó lọ sí orílẹ̀-èdè South Africa láti tún lọ kọ́ ìmọ̀ síwájú si.
Iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeÓ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí aṣara-lóge ní ọdún 2003,[4] tí ó sì tún bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré ṣíṣe ní àárín ọdún 2013. Ó ti gbé àwọn eré ọlọ́kan-ò-jọ̀kan eré tí ó ti gba àmì-ẹ̀yẹ jáde ní abẹ́ ilé-iṣẹ́ Kannywood àti Nollywood pẹ̀lú.[5]including Oga Abuja, which won Best Hausa Movie of the Year at the 2013 City People Entertainment Awards;[6] Ọ̀kan lára àwọn eré rẹ̀ tí ó gba àmì-ẹ̀yẹ Sinimá àgbéléwò tí ó dára jùlọ ní agbo Kannywood ní ọdún 2014 níbi ayẹyẹ "City People Entertainment Awards", tí wọ́n sì tún yàn fún àmì-ẹ̀yẹ "Eré tí àwòrán rẹ̀ dára jùlọ" níbi ayẹyẹ 2014 Nigeria Entertainment Awards ni Maja.[7]
Àwọn Àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀
àtúnṣeỌdún | Àmì-ẹ̀yẹ | Ìsọ̀rí | Eré\ | Àbájáde |
---|---|---|---|---|
2008 | Africa Movie Academy Awards | Best Make up | London Boy[8] | Gbàá |
2013 | City People Entertainment Awards | Best Movie of the Year - Kannywood | Oga Abuja | Gbàá |
2014 | Africa Magic Viewers Choice Awards | Best Movie of the Year | Oga Abuja | Gbàá |
2014 | City People Entertainment Awards | Best Movie of the Year - Kannywood | Maja | Gbàá |
2016 | African Hollywood Awards[9] | Best Film Producer | Oga Abuja | Gbàá |
Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀
àtúnṣeỌdún | Àkọ́lé | Ipa tí ó kó | Genre |
---|---|---|---|
2015 | Oga Abuja | Produced | Drama |
2015 | Maja | Produced | Drama |
2016 | Dark Closet | Produced | Drama |
2016 | Power of Tomorrow | Produced | Drama |
2016 | Hassana da Hussaina | Produced | Drama |
2015 | Har da mijina | Actor | Drama |
2019 | Muqabala (Season 1&2) | Produced & Actor | Drama |
2016 | Red Line | Produced | Drama |
Dear Affy | Actor | Drama | |
2017 | If I am President | Actor & Line Producer [10] | Drama |
2018 | Lagos Real Fake Life | Produced | Drama |
2018 | Mustapha | Actor | Drama |
2019 | 'Almost Perfect | Actor | Drama |
2019 | Least Expected | Produced & Actor | Drama |
2019 | Maimuna | Produced & Actor | Drama |
2018 | Sharo | Actor | Drama |
2020 | Good Citizen | Produced | Drama |
Ẹ tún lè wo
àtúnṣeÀwọn Ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Lere, Mohammed (July 11, 2013). "Kannywood, Nollywood comedy, 'Oga Abuja,' now on sale". Premium Times. Retrieved February 13, 2018.
- ↑ "PressReader.com – Connecting People Through News". www.pressreader.com. Retrieved February 14, 2018.
- ↑ "Emeka Ike, Uzee Usman, others honoured at the national heritage award – COMPLETE ENTERTAINMENT". tvcontinental.tv. May 7, 2016. Retrieved February 14, 2018.
- ↑ "Uzee: From makeup artist to film director". 24 April 2018. Retrieved 6 May 2020.
- ↑ Lere Mohammed (January 11, 2014). "I brought John Okafor, Nkem Owoh to Kannywood – Usman Uzee". Retrieved February 13, 2018.
- ↑ thenet (July 17, 2013). "Mary Uranta, Yul Edochie, Wizkid, Jackie Appiah, John Dumelo biggest winners at City People Awards". thenet.ng. Retrieved February 14, 2018.
- ↑ Editor (25 November 2014). "Nigerian Entertainment Awards 2014". Pulse. Archived from the original on July 8, 2018. Retrieved 14 February 2018.
- ↑ https://www.premiumtimesng.com/entertainment/153150-brought-john-okafor-nkem-owoh-kannywood-usman-uzee.html
- ↑ Lere, Mohammed (November 6, 2016). "Hadiza Gabon, Usman Uzee honoured at African Hollywood Awards". Premium Times. Retrieved February 13, 2018.
- ↑ https://www.imdb.com/title/tt9189476/fullcredits
- ↑ "IMDb". Retrieved 5 May 2020.