Uzo Aduba
Uzoamaka Nwanneka (bíi ni ọjọ́ kẹwàá oṣù kejì ọdún 1981)[1] tí orúkọ inagi rẹ jẹ Uzo Aduba[2] je òṣèré ni orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó gbajúmọ̀ fún ipa rẹ̀ nínú eré Orange is the New Black tí ó ti kó ipa Suzanne ni ọdún 2013-2019 ni ibi tí ó ti gbà ẹ̀bùn Outstanding Guest Actress ni ọdún 2014 àti Outstanding Supporting Actress ni ọdún 2015 láti ọ̀dọ̀ Screen Actors Guild Awards[3]. Uzo je ìkan láàrin àwọn òṣèré méjì tí ó ti gba ẹ̀bùn Emmy Award fun ẹ̀fẹ̀ atí eré orí ìtàgé.[4]
Uzo Aduba | |
---|---|
Uzo Aduba in 2014 | |
Ọjọ́ìbí | Uzoamaka Nwanneka Aduba 10 Oṣù Kejì 1981 Boston, Massachusetts, U.S. |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Boston University |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 2003–present |
Ní ọdún 2020, ó kó ipa Shirley Chisholm nínú eré Mrs America èyí sì lọ je ki o gba ẹ̀bùn Primetime Emmy Award for Outstanding Supporting Actress in a Limited Series or Movie.
Ìbẹ̀ẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ aiyé rẹ
àtúnṣeWọ́n bí Aduba sì ìlú Boston ni ilé Massachusetts.[5] Àwọn òbí rẹ sì jẹ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó dàgbà sì ilu Medfield ni Ilẹ̀ Massachusetts ó sì lọ sí ilé ẹ̀kọ́ tí Medfield High School.[6][7][8] Ó gboyè jáde láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Boston University.[9]
Iṣẹ́
àtúnṣeUzo tí kopa ninu awọn oríṣiríṣi ere, díẹ̀ lára àwọn eré tí ó ti kopa ninu ni Translations of Xhosa[10][11] ati Orange Is the New Black[12][13]
Awon Itokasi.
àtúnṣe- ↑ Wright, Celine (August 12, 2013). "'Orange Is the New Black's' Uzo Aduba on a good road as Crazy Eyes". Los Angeles Times.
32-year-old Aduba
- ↑ "Godspell Talk Back – Uzo Aduba". Reviewing The Drama. March 26, 2012.
- ↑ Emmy Awards 2015: The complete winners list.Beats 2019 CNN.com (September 21, 2015). Retrieved on December 7, 2015.
- ↑ "Uzo Aduba Watch 'OITNB' actress speak Igbo, reveal her favourite Nigerian dish,". Pulse.ng. Chidumga Izuzu. Archived from the original on January 29, 2016. Retrieved January 29, 2016.
- ↑ Aduba, Uzo (August 4, 2014). "Uzo Aduba: My Road to ‘Orange Is the New Black'". The Daily Beast
- ↑ "Medfield Native Uzo Aduba Attends White House Correspondents Dinner". medfield.patch.com. May 5, 2014.[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
- ↑ Champagne, Christine (June 8, 2014). "Behind the Breakout Role: Orange is the New Black's Uzo Aduba on Creating Crazy Eyes". Co.Create. Retrieved July 15, 2014.
- ↑ "2001–02 Women's Track Roster". Boston University. Archived from the original on March 25, 2016. Retrieved July 11, 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Boston University Meet Results". UMassAthletics.com. Archived from the original on October 29, 2013. Retrieved October 27, 2013. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Translations of Xhosa - Washington, DC - Tickets, Reviews, Info and More". theatermania. Archived from the original on November 7, 2017. Retrieved October 29, 2017.
- ↑ "Outstanding Supporting Actress, Resident Play – 2004". Awards and nominations Theatre Washington. Archived from the original on October 8, 2020. Retrieved October 27, 2013.
- ↑ Weber, Lindsey (July 24, 2013). "Orange Is the New Black's Uzo Aduba on Crazy Eyes, Flirting Techniques, and Peeing on the Floor". Vulture.com. New York City: New York Media. Retrieved July 28, 2013.
- ↑ Ryan, Maureen (August 23, 2013). "'Crazy Eyes' From 'Orange Is The New Black' Talks Flirting, Jodie Foster And That Infamous Scene". The Huffington Post. Retrieved October 27, 2013.