Venita apkofure
Venita Akpofure (bíi ní ọjọ́ kínní, oṣù kínní, ọdún 1987) Big Brother Naija (season 4)[1].ó jẹ́ òyìnbó-alawo dúdú British-Nigerian tó sì jẹ́ òṣèré amóhùnmáworan. [2]ó jẹ́ gbajùmọ̀, ìlú mòoká lẹ́yìn tí ó jáde nínú ilé Ẹ̀gbọ́n àgbà ìran ẹlẹ́ẹ̀kẹrin tí ayé mọ̀ sí Big Brother Naija Season 4 tí ó jé ara inú naa. Ò sí jẹ́ akópa nínú eré ojú èrò amóhùnmáworan orí AFRICA MAGIC tí àkọọlẹ rẹ jẹ́ UNMARRIED, èyí tí ó sí jẹ́ OLÚ ÒṢÈRÉ inú eré naa.
Venita Akpofure | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 1987 Britain |
Orílẹ̀-èdè | British-Nigerian |
Iṣẹ́ |
|
Gbajúmọ̀ fún |
|
Olólùfẹ́ | Tena Terka (div. 2019) |
Àwọn ọmọ | 2 |
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Augoye, Jayne (10 May 2020). "INTERVIEW: My Role in 'Unmarried' series and life after BBNaija – Venita Akpofure". Premium Times.
- ↑ Nwogu, Precious (20 January 2021). "'Unmarried' returns for its 2nd season this January". Pulse NG.