Vera Okolo jẹ ọkan lara agbabọọlu lobinrin órilẹ ede naigiria ti a bini 5, óṣu January ni ọdun 1985. Arabinrin naa ṣere fun team awọn obinrin ilẹ naigiria ti national lori bọọlu[1][2].

Vera Okolo
Personal information
OrúkọVera Okolo
Ọjọ́ ìbí5 Oṣù Kínní 1985 (1985-01-05) (ọmọ ọdún 39)
Ibi ọjọ́ibíNigeria
Ìga ft 0 in (0.00 m)
National team
Nigeria women's national football team
† Appearances (Goals).

Àṣeyọri

àtúnṣe
  • Vera ti ṣere fun Delta Queens ni ere idije awọn obinrin ilẹ naigiria[3].
  • Arabinrin naa ti wa lara team ti o kopa ninu olympic to waye ni ọdun 2004[4].
  • Vera ti jẹ àṣoju fun super falcons ni ere idije awọn obinrin ilẹ afirica ni ọdun 2004 to waye ni ilẹ south afirica[5]

Itọkasi

àtúnṣe
  1. https://int.soccerway.com/players/vera-okolo/291451/
  2. https://www.olympedia.org/athletes/103011
  3. https://allfamousbirthday.com/vera-okolo/[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  4. https://www.fifa.com/tournaments/womens/womensolympic/athens2004/teams/1882893
  5. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2022-05-29. Retrieved 2022-05-29.