Victor Boniface
Lát'ọwọ́ Wikipedia
Personal information | |||
---|---|---|---|
Full name | Victor Okoh Boniface | ||
Date of birth | 23 December 2000 (age 22) | ||
Place of birth | Akure, Ondo State, Nigeria | ||
Height | 1.90 m (6 ft 3 in) | ||
Position(s) | Forward | ||
Team information | |||
Current team | Bayer Leverkusen | ||
Number | 22 | ||
Youth career | |||
–2019 | Real Sapphire | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps | (Gls) |
2019–2022 | Bodø/Glimt | 48 | (13) |
2022–2023 | Union SG | 37 | (9) |
2023– | Bayer Leverkusen | 13 | (8) |
International career‡ | |||
2023– | Nigeria | 5 | (0) |
*Club domestic league appearances and goals, correct as of 23:43, 25 November 2023 (UTC)
‡ National team caps and goals, correct as of 19 November 2023 |
Victor Okoh Boniface
ti wọ́n bí ní ọjọ́ kẹtàlélólógún, oṣù Kejìlá ọdún 2000. Jẹ́ agbábọ́ọ̀lù ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà ní ọwọ́ iwájú fún ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Bayer Leverkusen àti tí ikọ̀ super eagle ti ilẹ̀ Nàìjíríà.
[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
àtúnṣeBodø/Glimt[àtúnṣe àmìọ̀rọ̀
àtúnṣeBoniface tọwọ́ bòwé fún ikọ̀ Bodo/Glimt láti inú ikọ̀ Real Sapphire ní ọjọ́ kẹrin oṣù kẹta ọdún 2019. Ó ní ìfarapa lẹhin bí ọ̀sẹ̀ méjì tí ó dara pọ̀ mọ́ ikọ̀ Glimt. Léyìí tí ó mú kí ó má lè kópa nínú sáà ọdún 2019.
Wọ́n mu Boniface sí inú ikọ̀ super eagle àwọn tí ọjọ́ orí wọn ò jú ogún ọdún lọ nínú ìdíje kọ́ọ̀pù ilẹ̀ Áfríkà tí ọjọ́ orí wọn kò ju ogún ọdún lọ. Ṣùgbọ́n ó ní láti kústo
úrò nínú ikọ̀ náà látàrí ìfara. Ní oṣù kẹsàn-án ó kópa fún ìgbà àkókò fún ikọ̀ ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù rẹ̀. a rẹ̀