Victor Oladokun
Victor Oladokun (tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ Victor Bandele Oladokun) ó jẹ́ oníròyìn, àti elétò ọ̀nà ìbánisọ̀rọ̀ ní Nigeria àti united kingdom. Ó jẹ́ Olùdarí fún ìbánisọ̀rọ̀ àti ìbáṣepọ̀ àwọn ará ilẹ̀ òkèrè African Development Bank AFDB [1][2] ó sì tún jẹ́ aṣagbátẹrù, àti olùgbàlejò fún gbajúgbajà ètò magasíìnì lórí amóhùnmáwòrán ti gbogbo àgbáyé. CBN World News and Turning Point on the Christian Broadcasting Network CBN.[3]
Victor Oladokun | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Victor Bandele Oladokun 26 Oṣù Kẹta 1958 England |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian British |
Ẹ̀kọ́ | Regent University Obafemi Awolowo University |
Iṣẹ́ | Broadcaster, TV host, journalist, media consultant |
Ìgbà iṣẹ́ | 1990–present |
Organization | Africa Development Bank Group |
Gbajúmọ̀ fún | Turning Point, CBN World News |
Awọn itọkasi
àtúnṣe- ↑ "UNGA 2019: Women are "Africa's tigers" says Congolese First Lady as African Development Bank touts $3bn fund | African Development Bank - Annual Meetings 2020". am.afdb.org.
- ↑ Clarke, Justice R. (6 June 2019). "Liberia: AfDB Sure Media Can Help Shape Mindset for Sustainable Development". allAfrica.com.
- ↑ "Victor Oladokun". 7 August 2017. Archived from the original on 29 March 2023. Retrieved 29 March 2023.