Victor Thompson (olórin)
Victor Ufuoma Thompson tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Victor Thompson (tí a bí ní ọjọ́ 11 Kọkànlá Oṣù 1986) jẹ́ akọrin ìhìnrere Nàíjíríà àti onkọ̀rin. Ó jẹ́ olókìkí fún orin “Odún Yi (Àwọn Ìbùkún)” tí o jáde ní Oṣù Kiní ọdún 2023.
Victor Thompson | |
---|---|
Orúkọ àbísọ | Victor Ufuoma Thompson |
Ọjọ́ìbí | 11 Oṣù Kọkànlá 1986 Lagos State, Nigeria |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Delta State |
Irú orin | |
Occupation(s) |
|
Instruments | Vocals |
Years active | 2017–present |
Website | victorthompsonmusic.com |
Ìgbésí ayé
àtúnṣeVictor Thompson ni wọ́n ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kọkànlá ọdún 1986 ní ìpínlè Èkó ní orílẹ̀ - èdè Nàìjíríà sùgbón ó wá láti Okpara-Inland ní ìjọba ìbílẹ̀ Ethiope East ní ìpínlẹ̀ Delta . Ó ti kọ́ ẹ̀kó alákobẹ̀ẹ́rẹ̀ rẹ̀ ní St Anthony Nursery and Primary School, lẹ́hìn na ó lọ sí Caleb International School, nígbà tí o ni ilé-ẹ̀kọ́ gíga rẹ̀ ni Government College, Ikorodu méjèèjì ni Ìpínlẹ̀ Èkó.
O gba oyè kíni láti Federal University of Petroleum Resources, Effurun, Delta State in Environmental Science.