Victoria Umunna
Victoria Umunna (tí wọ́n bí ní ọjọ́ kọkànlá oṣù kọkànlá ọdún 1973) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tó máa ń kópa nínú ìdíje bọ́ọ̀lù aláfọwọ́gbá. Ó kópa nínú ìdíje àwọn obìnrin ní 1992 Summer Olympics.[1][2]
Òrọ̀ ẹni | |
---|---|
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọjọ́ìbí | 11 Oṣù Kọkànlá 1973 |
Sport | |
Erẹ́ìdárayá | Handball |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "Olympedia – Victoria Umunna". Olympedia – Main Page. 1973-11-11. Retrieved 2024-04-25.
- ↑ Gbenga-Ogundare, Yejide (2023-05-03). "Quick take: Dehlia Victoria Umunna". Tribune Online. Retrieved 2024-04-25.