Vilma Espin
Vilma Lucila Espín Guillois (tí a bí ní ọjọ́ keje oṣù kẹrin ọdún 1930 tí ó sì kú ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹfà ọdún 2007) jẹ́ ọmọ ilẹ̀ Kuba bẹ́ẹ̀ sì ni ó tún jẹ́ ìyàwó Raul Kastro Ààrẹ ilẹ̀ Kuba. Ó kó ipa tí ó ṣe kókó nínú ìjà gbára ilé Cuba.
Vilma Espín | |
---|---|
Vilma Espin nígbà tí ó sì jẹ́ ọ̀dọ́bìnrin | |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 7 Oṣù Kẹrin 1930 |
Aláìsí | 18 June 2007 | (ọmọ ọdún 77)
Ẹbí | Fidel Castro (brother-in-law) Jose Espín (father) Margarita Guillois (mother) Nilsa Espín (sister) Iván Espín (brother) Sonia Espín (sister) José Espín (brother) |
Àwọn ọmọ | Deborah Castro Espín Mariela Castro Espín Nilsa Castro Espín Alejandro Castro Espín |
Awards | Lenin Peace Prize 1977-78 |
{{{blank1}}} | Raúl Castro |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |