Adeline Virginia Woolf (pronounced /ˈwʊlf/; 25 January 1882 – 28 March 1941) je olukowe, akoayoka, atewejade ati oluda ara Ilegeesi, o je gbigba bi ikan ninu awon aseodeonimodernist onimookomooka igba orundun 20.

Virginia Woolf
Ọjọ́ ìbíAdeline Virginia Stephen
(1882-01-25)25 Oṣù Kínní 1882
London, England, UK
Ọjọ́ aláìsí28 March 1941(1941-03-28) (ọmọ ọdún 59)
near Lewes, East Sussex, England
Iṣẹ́Novelist, Essayist, Publisher, Critic
Notable worksTo the Lighthouse, Mrs Dalloway, Orlando: A Biography, A Room of One's Own
SpouseLeonard Woolf (1912–1941)