Wajir Museum (Swahili: Makumbusho ya Wajir; Àdàkọ:Lang-so) jẹ́ musíọ́mù kan tí ó wà ní àríwá ìlà oòrùn Kenya. Musíọ́mù náà ń ṣe àfihàn àwọn oríṣiríṣi ẹ̀yà àti àsà àwọn tí ó gbé Wajir. Musíọ́mù náà wà lábẹ́ ìdarí National Museums of Kenya Corporation. Òun ni musíọ́mù àkọ́kọ́ ní Wajir County.[1]

Wajir Museum
Building
LocationWajir, Kenya

Ìtàn àtúnṣe

Musíọ́mù náà wà ní Wajir, òun sì ni wọ́n kọ́kọ́ dálẹ̀ ní Wajir, àwọn ẹrú Italy tí wọ́n kó lógun sì ló kọ́ ilé náà.[2] Ara ìdí tí wọ́n ṣe dá musíọ́mù náà kalẹ̀ ni láti fa àwọn arin ìrìn àjò mọ́ra sí àríwá Kenya.[3] Mínísítà Mohammed Ibrahim Elmi ló ṣe àfilọ́lẹ̀ Musíọ́mù náà. Àjọ musíọ́mù ní Kenya fún musíọ́mù náà ni DVD player, solar power system àtí TV set.[4] Ní oṣù Kejìlá ọdún 2015, wọ́n ṣe ayẹyẹ àṣà Wajir èkejì ní musíọ́mù náà, àjọ National Museums of Kenya àti ìjọba Wajir County ló ṣe igbá tẹrù rẹ̀.[5]

Àwọn Ìtọ́kasí àtúnṣe

  1. "Wajir Country Integrated Development Plan 2018-2022" (PDF). Ministry of Devolution. 2020. Archived from the original (PDF) on 2021-12-16. Retrieved 2021-12-15.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  2. Muchui, David (2020-07-02). "Tour Wajir for a feel of WWII, cultural heritage". Nation (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-12-16.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "Wajir Museum: Geographical location and historical background" (PDF). Wajir Live. 2012. Retrieved 2021-12-15.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  4. Mbuthia, David (2013). "New museum spotlights region with ambitions for tourism" (PDF). Kenya Museum Society. Retrieved 2021-12-15.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. "National Museums of Kenya 2015-2016 Annual Report" (PDF). National Museums of Kenya. Retrieved 2021-12-21.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)