Ọdún 1969 ni wọ́n Wale Adebanwi, ọmọ Orílẹ̀èdè Nàìjíríà ni. Òun ni ọmọ ilẹ̀ Adúláwọ̀ àkọ́kọ́ láti jẹ́ Ọ̀jọ̀gbọ́n Rhodes ni Kọ́lẹ́jì St. Anthony ní ìlú Oxford. Ó jẹ́ Ọ̀jọ̀gbọ́n ajẹmọ́ ẹ̀ka ẹ̀kọ́ ni Awo, tí ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olórí ilé ẹ̀kọ́ náà títí di oṣù Òkudù. Òun ni Ọ̀jọ̀gbọ́n ẹ̀ka ìmọ̀ ajẹmọ - Adúláwò ni Yunifasiti Pennsylvania

Ètò Ẹ̀kọ́

àtúnṣe

Wale Adebanwi kọ́kọ́ kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú kọ́ọ̀sì àkọ́kọ́ ní Yunifásítì ti Èkó, ó sì tẹ̀síwájú láti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè M.Sc àti Ph.D ni ẹ̀kọ́ ajẹmọ́ṣèlú ní Yunifasiti tí Ìbàdàn. Bákan náà ló ni òye Mphil àti Ph.D nínú imọ̀ ajẹmásà àwùjọ ní Yunifásítì Cambridge.

Social Anthropologi láti ile-iwe giga University of Cambridge.[1]

Ìgbésí ayé

àtúnṣe

Adebanwi ṣisẹ́ gẹ́gẹ́ bíi oníròyìn gbogbogbo, òǹkọ̀wé, oníròyìn àti olótùú fún iléeṣẹ́ ìwé - ìròyìn kí ó tó darapọ̀ mọ́ Yunifásítì ti Ìbàdàn láti lọ kẹ́kọ̀ọ́ imọ̀ ajẹmọ́ṣèlú gẹ́gẹ́ bí Olùkọ́ àti aṣèwádìí. Wọ́n yàn án ni Amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ Ọ̀jọ̀gbọ́n ní ẹ̀ka ẹ̀kọ́ nípa àwọn Adúláwọ̀ ní ìlú Amẹ́ríkà àwọn Adúláwọ̀ papọ̀ ní Yunifásítì California, Davis lórí èdè Ìlú Amẹ́ríkà. Ó padà sí UC Davis gẹ́gẹ́ bí Ọ̀jọ̀gbọ́n ní ọdún 2016

Àwọn Iṣẹ́ rẹ̀

àtúnṣe

Àwọn iṣẹ́ àtẹ̀jáde ré ní wọ̀nyí::[2]

  • Nation as Grand Narrative: The Nigerian Press and the Politics of Meaning (University of Rochester Press, 2016)
  • Yoruba Elites and Ethnic Politics in Nigeria: Obafemi Awolowo and Corporate Agency (Cambridge University Press, 2014)
  • Authority Stealing: Anti-corruption War and Democratic Politics in Post-Military Nigeria (Carolina Academic Press, 2012)

Ní àfikún , ó ṣàtúnṣe àwọn ìwé mìíràn bíi:

  • The Political Economy of Everyday Life in Africa: Beyond the Margins (James Currey Publishers, 2017)
  • Writers and Social Thought in Africa (Routledge, 2016)
  • (co-edited with Ebenezer Obadare) Governance and the Crisis of Rule in Contemporary Africa (Palgrave Macmillan, 2014)
  • (co-edited with Ebenezer Obadare) Democracy and Prebendalism in Nigeria: Critical Interpretations (Palgrave Macmillan, 2013).
  • (co-edited with Ebenezer Obadare) Nigeria at Fifty: The Nation in Narration (Routledge, 2012)
  • (co-edited with Ebenezer Obadare) Encountering the Nigerian State (Palgrave Macmillan, 2010).

Ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Naijamotherland. "Wale Adebanwi: Meet The Nigerian Appointed As First Black African Rhodes Professor At Oxford University". Naija Motherland. Archived from the original on 18 January 2017. Retrieved 28 February 2017. 
  2. Nigeriannation. "Wale Adebanwi: Meet The Nigerian Appointed As First Black African Rhodes Professor At Oxford University". Nageriannation.news. Archived from the original on 1 March 2017. Retrieved 28 February 2017.