Olóyè Wale Ogunyemi, OFR (Oṣù Ògún, Ọdún 1939 sí Oṣù Ọ̀pẹ, Ọdún 2001)jẹ́ àgbà-ọ̀jẹ̀ eléré onísẹ́, òṣeré, ògbóǹtarìgì ọ̀ǹkọ̀tàn eré onísẹ́ àti onímọ̀ èdè Yorùbá ọmọ Orílẹ̀èdè Nàìjíríà Yoruba[2]

Wale Ogunyemi
Ọjọ́ìbí12 August 1939
Osun State, Nigeria.
AláìsíDecember 2001
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigerian
Iṣẹ́playwright
Ìgbà iṣẹ́1963–present
Gbajúmọ̀ fún
The Lion and the Jewel
Kongi's Harvest
Sango
Langbodo[1]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ Ìgbé -Ayé àtúnṣe

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ìgbé ayé. Ọjọ́ kejìlá  Oṣù Ògún ọdún 1939 ni wọ́n bí i sí ní ìlú Ìgbájọ, Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun, apá ìwọ̀ oòrùn Nàìjíríà. Àwọn òbí rẹ̀ ni kúSamuel Adéọ̀ṣun àti Mary Ògúnyẹmí. Ó lọ sí Yunifásítì ti Ìbàdàn ní ọdún 1976 láti kẹ́kọ̀ọ́ ọlọ́dún kan nínú eré onísẹ́, ọdún yìí kan náà ni wọ́n yàn án ní amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ aṣèwádìí ní Ibùdó Ìmọ̀ Ìbàdàn tí Èkọ́ nípa Adúláwò níbi tí ó ti padà fẹ̀yìntì.

un[3]n.[4][5][6]

Iṣẹ́ àtúnṣe

Iṣẹ́: Ní bí ọdún 1960 síwájú ló bẹ̀rẹ̀  bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré onísẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi ògbóǹtarìgì òṣeré pẹ̀lú Iléeṣé Tẹlifíṣàn Apá ìwọ̀ oòrùn Nàìjíríà. Bákan náà ló ṣisẹ́ pẹ̀lú Ọ̀jọ̀gbọ́n Wọlé Ṣóyinká, tí ó sì padà wà lára àwọn ọmọ ẹgbẹ́ olùdásílẹ̀ Ṣóyinká Orísun theatre. Ó di ààyò láti kópa nínú àwọn eré Wọlé Ṣóyinká, níbi tí ó ti kópa ẹ̀dá ìtàn "Baálẹ̀"  nínú Lion and the Jewel"  àti Dende nínú Kongi's Harvest nítorí pé ó fakọyọ nínú ìkópa rẹ̀ ṣáájú. Bákan náà ló Kópa nínú "The Beautification of Area Boy, eré onísẹ́ Wọlé Ṣóyinká tí wọ́n se àfihàn àkọ́kọ́ rẹ̀ ni West Yorkshire Playhouse ní ọdún 1995. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìwé eré onísẹ́ ló ti dá kọ, tí ó sì ṣe àjùmọ̀kọ náà pẹ̀lú àwọn ẹlòmíràn kí ó tó di olóògbé ni Oṣù Ọ̀pẹ, Ọdún 2001.[7] .[8] [9].[10].[11].[12][13]

ÀKÓJỌPỌ̀ ERÉ ORÍ ÌTÀGÉ ÀTI FÍÌMÙ àtúnṣe

The Lion and the Jewel

Kongi's Harvest

Sango (1997)

The Beatification Of Area Boy[14][15]

The Ijaye War (1970)[16]

Kiriji (1976)[17]

The Divorce (1975)[18]

Aare Akogun (1968)

Everyman *Eniyan, 1987)

Langbodo (1979)[19]

ÀWỌN OYÈ ÌDÁNILỌ́LÁ àtúnṣe

Ààrẹ Orílẹ̀èdè fi oyé pàtàkì dá a lọ́la gẹ́gẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ apàsẹ Orílẹ̀èdè Nàìjíríà

Olóyè Májẹ̀óbàjẹ́ ti ìlú Òkukù, oyè tí Olókukù tí ìlú Òkukù fi dá a lọ́lá

Májẹ̀óbàjẹ́ ti ìlú Òkukù, oyè tí Olókukù tí ìlú Òkukù fi dá a lọ́lá


íibỌmọ


pàsẹa Opẹ̀lú àṣẹ Ààrẹ Orílẹ̀èdè Nàìjíríà. Májẹ̀óbàjẹ́ ti ìlú Òkukù, oyè tí Olókukù tí ìlú Òkukù fi dá a lọ́lá



Awon itokasi àtúnṣe

  1. "Set to battle demons on mount Langbodo". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Archived from the original on 18 January 2015. Retrieved 18 January 2015. 
  2. Black African Literature in English, 1997-1999. https://books.google.nl/books?id=rAUbyu1wRCsC&pg=PA312&lpg=PA312&dq=Wale+Ogunyemi,+script+writer&source=bl&ots=vkzFLVY14G&sig=ZyxxjKFasOKrFvpo0npZSJR4eos&hl=en&sa=X&ei=ZX-7VJz-FMf6PM2YgeAE&ved=0CBAQ6AEwAg. Retrieved 18 January 2015. 
  3. Ọdún. https://books.google.com.ng/books?id=9PsbR01ZUTAC&pg=PA24&lpg=PA24&dq=Wale+Ogunyemi,+a+writer+of+all+time&source=bl&ots=7IagELpJfm&sig=yg9LmdMiTlIAHqCemhWa6l6tup8&hl=en&sa=X&ei=ENK7VPHQKsXgOMa_gYgB&redir_esc=y. Retrieved 18 January 2015. 
  4. European-language Writing in Sub-Saharan Africa. https://books.google.nl/books?id=D6PrqVKaZtgC&pg=PA774&lpg=PA774&dq=Wale+Ogunyemi,+script+writer&source=bl&ots=JCZr5Atl3B&sig=OaU3ILAvvZItUgqLABwTbmaIJ4w&hl=en&sa=X&ei=ZX-7VJz-FMf6PM2YgeAE&ved=0CBUQ6AEwBA. Retrieved 18 January 2015. 
  5. Relocating Agency. https://books.google.nl/books?id=RTzibTsqLE4C&pg=PA206&lpg=PA206&dq=Langbodo+by+Wale+Ogunyemi&source=bl&ots=LGSxVo-WSF&sig=i9YjPPGBwJUb6Z3J67vs32m81xw&hl=en&sa=X&ei=AtW7VIOcJYfvOdGogfgJ&ved=0CAsQ6AEwADgU. Retrieved 18 January 2015. 
  6. The Columbia Guide to West African Literature in English Since 1945. https://books.google.nl/books?id=VaZx0Q2O3l8C&pg=PA150&lpg=PA150&dq=Langbodo+by+Wale+Ogunyemi&source=bl&ots=k9MdiBPLed&sig=g8ucXOyOEHd_eZz1w4o3eNCBA1I&hl=en&sa=X&ei=AtW7VIOcJYfvOdGogfgJ&ved=0CBsQ6AEwBjgU. Retrieved 18 January 2015. 
  7. "The Nostalgic Drum". google.nl. Retrieved 18 January 2015. 
  8. "WHY WALE OGUNYEMI STILL LIVES ON NIGERIA'S STAGE-DIRECTOR OF LANGBODO". thenigerianvoice.com. Retrieved 18 January 2015. 
  9. Who's Who in Contemporary World Theatre. https://books.google.nl/books?id=dJSFAgAAQBAJ&pg=PA227&lpg=PA227&dq=Wale+Ogunyemi+featured+in+The+lion+and+the+jewel&source=bl&ots=XiWZXOFjaB&sig=2gauiC_ZAfPIU7Me3lgmDfjSHvg&hl=en&sa=X&ei=z4G7VIjnM4GdPemXgNAJ&ved=0CA4Q6AEwAQ. Retrieved 18 January 2015. 
  10. Childhood in African Literature. https://books.google.nl/books?id=WEArQ7PQgw4C&pg=PA140&lpg=PA140&dq=Wale+Ogunyemi,+script+writer&source=bl&ots=2_lRB8TSL1&sig=gsRkyybFSi3tF68DxbquPaf4wt0&hl=en&sa=X&ei=6oC7VNztMszjO768gZgB&ved=0CCEQ6AEwBzgK. Retrieved 18 January 2015. 
  11. "Obituary: Wale Ogunyemi". the Guardian. Retrieved 18 January 2015. 
  12. Fertile Crossings. https://books.google.com.ng/books?id=9KhDYdn6myMC&pg=PA215&lpg=PA215&dq=Wale+Ogunyemi,+a+writer+of+all+time&source=bl&ots=umCpdvTR2P&sig=tD9mg6i4eVcuOKBv2T0dFAA5JRk&hl=en&sa=X&ei=ENK7VPHQKsXgOMa_gYgB&redir_esc=y. Retrieved 18 January 2015. 
  13. "Student Encyclopedia of African Literature". google.nl. Retrieved 18 January 2015.