Adéwálé "Wally" Adéyẹmọ (wọ́n bí i lọ́dún 1981)[1] jẹ́ Ààrẹ àkọ́kọ́ fún àjọ-aṣàánú, Obama Foundation tí Ààrẹ àná orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà, Barack Obama dá sílẹ̀. [2] During the Obama Administration, Adéyẹmọ ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí igbákejì olúdámọ̀ràn lórí ètò àbò fún àjọ ètò ọ̀rọ̀-ajé àgbáyé,International Economics lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà lọ́dún 2015 sí 2016, bẹ́ẹ̀ náà òun ni igbá-kejì ọ̀gá àgbà ti National Economic Council.[3]

Wally Adéyẹmọ
Official portrait, 2021
15th United States Deputy Secretary of the Treasury
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
March 26, 2021
ÀàrẹJoe Biden
SecretaryJanet Yellen
AsíwájúJustin Muzinich
President of the Obama Foundation
In office
August 1, 2019 – March 25, 2021
AsíwájúPosition established
Arọ́pòValerie Jarrett
United States Deputy National Security Advisor for International Economics
In office
2015–2016
ÀàrẹBarack Obama
AsíwájúCaroline Atkinson
Arọ́pòDaleep Singh (2021)
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí
Adewale O. Adeyemo

20 Oṣù Kàrún 1981 (1981-05-20) (ọmọ ọdún 43)
Ibadan, Nigeria
Ọmọorílẹ̀-èdèAmerican
Ẹgbẹ́ olóṣèlúDemocratic
Education

Ìgbésí ayé rẹ̀ ní ìbẹ̀rẹ̀

àtúnṣe

Adéyẹmọ dàgbà sí Los Angeles, California.[4] Ó kàwé gboyè Bachelor of Arts láti University of California, Berkeley àti Juris Doctor láti Yale Law School.[5]

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. "Adewale Adeyemo: President of Obama Foundation". Leadership. August 11, 2019. Retrieved November 29, 2020. 
  2. "Obama Foundation Announces Wally Adeyemo as President". Obama Foundation (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-11-30. 
  3. "Statement by the President on the Selection of Adewale Adeyemo as Deputy National Security Advisor". whitehouse.gov (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2015-12-15. Retrieved 2020-11-30. 
  4. "Board of Trustees". Demos (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-11-30. 
  5. Rachlin, Jill. "Wally Adeyemo". Reiss Center on Law and Security (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-06-06.