Warner Baxter
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America
Warner Leroy Baxter (March 29, 1889 – May 7, 1951) jẹ́ òṣèré ará Amẹ́ríkà, tó gbajúmọ̀ fún iṣẹ́ rẹ̀ bíi The Cisco Kid nínú filmu In Old Arizona (1929), èyí tó gba Ẹ̀bùn Akádẹ́mì fún Ọkùnrin Òṣèré Tódárajùlọ ní ọdún 1928-1929.[1]
Warner Baxter | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Warner Leroy Baxter Oṣù Kẹta 29, 1889 Columbus, Ohio, Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà |
Aláìsí | May 7, 1951 Beverly Hills, California, Orílẹ̀ èdè Nàìjíríà | (ọmọ ọdún 62)
Iṣẹ́ | Òṣèré |
Ìgbà iṣẹ́ | 1914–1950 |
Olólùfẹ́ | Viola Caldwell (1911-1913) Winifried Bryson (1918–1951) |
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ Cliff Aliperti (29 March 2010). "Warner Baxter-A Brief Biography". Things and Other Stuff. Retrieved 2011-11-16.