Wendy Lawal
Yewande Lawal Simpson gbó jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Àwọn ènìyàn mọ́ tẹ́lẹ̀rí sí Yewande Lawal Adebisi.[1] Òun ni ó jáwé olúborí nínú ìdíje Miss Lagos Carnival Pageant ní ọdún 2012.[1][2]
Yewande Lawal Simpson | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Yewande Lawal Adebisi Ọjọ́ karúndínlọ́gbọ̀n oṣù kejì ọdún 1991 |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Ẹ̀kọ́ | Bachelor's degree in Creative Arts, University of Lagos, Nigeria |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Yunifásitì ìlú Èkó |
Iṣẹ́ | Òṣerébìnrin |
Ìgbà iṣẹ́ | 2009 - present |
Olólùfẹ́ | Wanri Simpson |
Ìtàn rẹ̀
àtúnṣeYetunde ni ọmọ karùn-ún nínú ọmọ mẹ́fà tí àwọn òbí rẹ̀ bí. Lawal fẹ́ Wanri Simpson ní ọdún 2018.[1] Ó sì pàdánù ìyá rẹ̀ ní ọdún 2020.[2][3]
Ẹ̀kọ́ rẹ̀
àtúnṣeLawal's ka ẹ̀kọ́ àkọ́bẹ̀rẹ̀ àti sẹ́kọ́ndírì rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Nigeria, ó sì tún tẹ̀síwájú láti gba àmì-ẹ̀yẹ bachelor's degree rẹ̀ nínú ìmọ̀ Creative Arts ní Yunifásítì ìlú Èkó.[1]
Iṣẹ́ rẹ̀
àtúnṣeIṣẹ́ Lawal nínú ṣíṣe fíìmù bẹ̀rẹ̀ ni ọdún 2009 lẹ́yìn ìgbà tí ó ṣeré nínú fíìmù Living in Lagos.[1][4] Lẹ́yìnhìgbà náà, ó ti ṣeré nínú ọ̀pọ̀lọpọ̀ fíìmù bias: The men's club, Jemeji, Journey to self, The room, Out of sight, Foreign Love.[1]
Àtòjọ àwọn fíìmù kọ̀kan tí ó ti ṣeré
àtúnṣe- Tinsel (2008)[1]
- Journey to Self (2012)[1]
- The Men's Club (2018)
- The Auction (2018)
- Jimeji (20)[5]
- The Room (20)
- Unbreakable (2019)
- The Set up (2019)[6]
Àwọn Ìtókasí
àtúnṣe- ↑ 1.0 1.1 1.2 1.3 1.4 1.5 1.6 1.7 "Wendy Lawal Biography | Profile | Fabwoman". FabWoman | News, Style, Living Content For The Nigerian Woman (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-02-25. Retrieved 2021-10-27.
- ↑ 2.0 2.1 Silas, Don (2020-11-13). "Tinsel Star, Wendy Lawal loses mother". Daily Post (Nigeria) (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-10-27. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Odutuyo, Adeyinka (2020-11-13). "Nollywood's Wendy Lawal left heartbroken as her mother dies". Legit.ng - Nigeria news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-10-27. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Falade, Tomi (2018-04-21). "Even With My Ring, Men Still Make Advances – Tinsel Star, Wendy Lawal". Independent Nigeria Newspaper (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-10-27. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Izuzu, Chibumga (2017-06-08). "Who is your favourite character on "Jemeji"?". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-10-27. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Jim Iyke, Adesua Etomi, Thrill in 'The Set Up'". THISDAY LIVE (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-06-22. Retrieved 2021-10-27. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help)