Werewere Liking (ti a bi ni odun 1950, ni ilu Cameroon) je onkowe ati osere ti on gbe ni Abidjan, Cote d’Ivoire. O da egbe ori itage Ki-Yi Mbock kale ni odun 1980, osi da abule Ki-Yi kale ni odun 1985 fun eko imo aworan fun awon odo.[1][2]

Werewere Liking

Iwe e Elle sera de jaspe et de corail je iwe orin ti o soro nipa misovire nipa kiko iwe iroyin oni ti o da lori nkan mesan. Ohun ni oko iwe awon ajafeto obinrin "misovirism"[3]

O gba ami eye Prince Clause ni odun 2000 fun ipa re si asa ati ise, o tun gba ami eye Noma ni odun 2005 fun iwe e La mémoire amputée.[4]

Awon Iwe Ti O ko àtúnṣe

Awọn iwe ati awọn ere rẹ pẹlu:

  • La mémoire amputée, Nouvelles Editions Ivoiriennes (2004), ISBN 2-84487-236-0
  • Elle sera de jaspe et de corail, Editions L'Harmattan (1983), ISBN 2-85802-329-8 - trans. Marjolijn De Jager, It shall be of jasper and coral; and, Love-across-a-hundred-lives (two novels), University Press of Virginia (2000), ISBN 0-8139-1942-8
  • La puissance de Um (1979) and Une nouvelle terre (1980) - trans. Jeanne Dingome, African Ritual Theatre: The Power of Um and a New Earth, International Scholars Pubs. (1997), ISBN 1-57309-066-2

Siwaju sii kika àtúnṣe

  • Simon Gikandi, Encyclopedia of African Literature, Routledge (2002), ISBN 0-415-23019-5 - pp. 288–9
  • Katheryn Wright, Extending generic boundaries: Werewere Liking's L'amour-cent-vies, in Research in African Literatures, June 2002 accessed at [1] March 5, 2007
  • Don Rubin, World Encyclopedia of Contemporary Theatre: Africa, Routledge (2000), ISBN 0-415-22746-1
  • Nicki Hitchcott, Women Writers in Francophone Africa, Berg Publishers (2000), ISBN 1-85973-346-8 - focuses on Mariama Bâ, Aminata Sow Fall, Werewere Liking and Calixthe Beyala: see publisher's details [2]
  • Peter Hawkins, Werewere Liking at the Villa Ki-Yi, in African Affairs, Vol.90, No.359 (Apr. 1991), pp. 207–222 - accessed at [3] March 1, 2007

Awọn akọsilẹ àtúnṣe

  1. https://howlround.com/interview-werewere-liking-theatre-company-village-ki-yi-mbock-interview-avec-werewere-liking-du
  2. https://www.jstor.org/stable/10.2979/meridians.13.1.186
  3. Zabus, Chantal J. (2013) (in en). Out in Africa: Same-sex Desire in Sub-Saharan Literatures & Cultures. Boydell & Brewer Ltd. pp. 148. ISBN 978-1-84701-082-7. https://books.google.com/books?id=_GPlAgAAQBAJ. 
  4. "Noma Award 2005". Archived from the original on 2007-03-04. Retrieved 2007-03-01.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)

Awọn ọna asopọ ita àtúnṣe