Wiki Indaba
Wiki Indaba jẹ́ àpéjọ òṣìṣẹ́ ti Wikimedia Foundation pẹ̀lú ìfẹ́ láti kó àti kọ́ ìmọ̀ nínú àwọn ọ̀rọ̀ àti ìṣe Ilẹ̀ Áfíríkà.[1][2] Àwọn kókó ìgbéjáde àti ìjíròrò pẹ̀lú àwọn iṣẹ́ àkànṣe Wikimedia gẹ́gẹ́ bí Wikipedia, wiki mìíràn, open-source software, ìmọ̀ ọ̀fẹ́, àkóónú ọ̀fẹ́ àti bí àwọn iṣẹ́ àkànṣe wọ̀nyí ṣe ní ipa lórí Ilẹ̀ Áfíríkà.
WikiIndaba | |
---|---|
Status | Active |
Genre | Conference |
Location(s) | Various |
Inaugurated | 2014 |
Most recent | 2021 |
Organised by | Local volunteer teams |
Filing status | Non-profit |
Website | wikiindaba.net |
Ajákálẹ̀-arùn Covid 19
àtúnṣeṢáájú ajákálẹ̀-arùn Covid 19, àwọn ẹgbẹ́ onímọ̀ Wikipedia aláfaramọ́ tí a yàn láti gbàlejò àpéjọ náà yóò ṣètò láti gbàlejò ní ènìyàn. Síbẹ̀síbẹ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀ àrùn ti Covid 19 ọ̀nà àgbékalẹ̀ yìí ti yípadà sí ọ̀nà ìlò ẹ̀rọ ayélujára níbití àwọn olùkópa lè lọ sí méjèèjì lórí ayélujára àti ní ara. Uganda jẹ́ orílẹ̀-èdè aláfaramọ́ àìpẹ láti gbàlejò rẹ̀ lórí ẹ̀rọ̀ ayélujára nìkan ní ọdún 2021 èyítí a rí àwọn nọ́mbà àwọn olùkópa ní ìlọ́po méjì láti ìgbà tí ó gbàlejò ní ènìyàn.
Àkòpọ̀
àtúnṣeÀmì | Iṣẹ́ Àkànṣe | Ọjọ́ | Orílẹ̀-èdè tó gba àlejò |
---|---|---|---|
WikiIndaba 2014 | June 20–22 | Johannesburg, South Africa[3] | |
WikiIndaba 2017[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́] | January 20–22 | Accra, Ghana[4] | |
WikiIndaba 2018 | March 16–18 | Tunis, Tunisia[5] | |
WikiIndaba 2019 | November 8–10 | Abuja, Nigeria[6] | |
WikiIndaba 2021 | November 5–7 | Kampala, Uganda |
Àwọn Ìtọ́ka Sí
àtúnṣe- ↑ Fripp, Charlie (2014-06-24). "What does Wikipedia need to do in Africa?". htxt.africa. Retrieved 2017-01-21.
- ↑ "Wiki Indaba 2017" (in en). Opensource.com. Archived from the original on 2020-04-13. https://web.archive.org/web/20200413135736/https://opensource.com/event/wiki-indaba-2017.
- ↑ June, Charlie Fripp on 24th (2014-06-24). "What does Wikipedia need to do in Africa?". htxt.africa. Retrieved 2017-02-08.
- ↑ "Wiki Indaba Kickstarts in Accra, Ghana - The African Dream". www.theafricandream.net (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 15 January 2017. Retrieved 2018-04-29.
- ↑ "WikiIndaba conference 2018". Retrieved 2017-12-24.
- ↑ "WikiIndaba conference 2019". Retrieved 2019-08-25.