Wikipedia:Àmì Wikipedia fún ìparẹ́ láìrosẹ̀

criteria for speedy deletion (CSD) tí a mọ̀ sí ìbámu fún píparẹ́ láìrosẹ̀ sọ pàtó ọ̀nà tí àwọn alámójúto ti ní ìpohùnpọ̀ láti pa ojú ewé Wikipeedia rẹ́ láì sí ìjomitoro lórí ojú ewé naa.  Wọ́n sì gbọ́dọ̀ tẹ́lé àwọn òfin tí a kaa síbí.


Píparẹ́ lè di ìyípodà, ṣùgbọ́n àwọn alábójútó ló lè yíi padà, àwọn píparẹ́ míràn maa ṣelẹ̀ lẹ́yìn ìjomitoro lórí ẹ̀, àyàfi ti wọ́n bá dáalába fún píparẹ. Píparẹ́ láìrosẹ̀ kìí jẹ́ kí àwọn ènìyàn fi àkókò ṣòfò lórí ìjomitoro lórí àwọn ojú ewé tàbí mídíà tí kò àyé wípé wọ́n maa dúro lẹ́yìn ìjomitoro.[1]

Ẹnikẹ́ni ní ó lè bèrè fún píparẹ́ láìrosẹ̀ látàri fífi àdàkọ píparẹ́ láìrosẹ̀ sí ojú ewé. 

The Ẹ̀ni tí ó bá dá ojú ewé lè má lè yọ àdàkọ  píparẹ́ láìrosẹ̀  kúrò ní ojú ewé tí wọ́n bá kọ. Ẹni tí kò kọ ojú ewé ni ó lè yọọ́. Tí ẹní tí ó kọ ojú ewé kò bá gbà kí ó ni tí o kọ́, kí ó tẹ bọ́tìnì Contest this speedy deletion tí ó wà lẹ́gbẹ́ àmì píparẹ́ láìrosẹ̀. Bọ́tìnì yìí maa jásí ọ̀rọ̀ ojú ewé tí a fẹ́ parẹ́ pẹ̀lú àyè láti ṣàlàyé ìdí tí ko fi gbọ́dọ̀ dí píparẹ́ láìrosẹ̀. Tí ẹni tí ó bá kọ àyọkà bá pa ojú ewé rẹ (tí kìí ṣe ojú ewé oníṣẹ́ tàbí ojú ewé ẹ̀ka), a lè kaa sí ìbeerè fún píparẹ́ a ó gbẹ́,  {{Db-blanked}} sí ojú ewé náa  (wo G7).

Àfihàn àwọn ààmì

àtúnṣe

Àgékúrú  (G12, A3...) ni a maa ń lò láti tọ́ni sí àwọn ààmì. Fún àpẹẹrẹ, "CSD G12" tọ́ni sí ààmì kejìlá lábẹ́ àpapọ̀  (àdàkọ ìṣẹ́ tí kìí ṣe tìrẹ) àti "CSD U1" tọ́ni sí ààmì àkọ́kọ́ làbẹ́ oníṣẹ́ (ìbẹ́èrè oníṣẹ́).

Àkójọ àwọn ààmì fún píparẹ́ láìrosẹ̀

àtúnṣe

Wo w:Wikipedia:Criteria for speedy deletion

Lápapọ̀

àtúnṣe

See also

àtúnṣe

Footnotes

àtúnṣe
  1. In this context, "speedy" refers to the simple decision-making process, not the length of time since the article was created.