Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 11 Oṣù Kàrún
- 1820 – Ìfilọ́lẹ̀ HMS Beagle, ọkọ̀-ojúomi tó gbé Charles Darwin lọ sí ìrìn-àjò iṣẹ́ sáyẹ́nsì rẹ̀.
- 1927 – Ìdásílẹ̀ Akadẹ́mì Iṣẹ́ọnà Àwòrán Ìmúrìn àti Sayẹ́nsì.
- 1949 – Siam yí orúkọ oníbiṣẹ́ rẹ̀ sí Thailand fún ìgbà kejì. Orúkọ yìí ti jẹ́ lílò láti 1939 sùgbọ́n ó jẹ́ yíyípadà ní 1945.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1904 – Salvador Dalí, akun-àwòrán ará Spẹ́ìn (al. 1989)
- 1918 – Richard Feynman, aṣiṣẹ́ẹ̀dá ará Amẹ́ríkà (al. 1988)
- 1933 – Louis Farrakhan, olórí Nation of Islam ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1934 – Blaise Diagne, olóṣèlú ará Sẹ̀nẹ̀gàl (ib. 1872)
- 1981 – Bob Marley (fọ́tò), olórin ará Jamáíkàn (ib. 1945)
- 1996 – Nnamdi Azikiwe, Ààrẹ Nàìjíríà àkọ́kọ́ (ib. 1904)