Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 29 Oṣù Kẹ̀sán
- 1911 – Italy gbógun ti Ottoman Empire.
- 1949 – Ẹgbẹ́ Kọ́múnístì ilẹ̀ Ṣáínà kọ ìwé Ètò Kannáà fún ojọ́ọwájú Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ènìyàn ilẹ̀ Ṣáínà.
- 1991 – Ológun fipá gbà ìjọba ní Haiti.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1571 – Caravaggio, oníṣọ̀nà ará Italia (al. 1610)
- 1901 – Enrico Fermi, aṣefísíksi ará Italia (al. 1954)
- 1943 – Mohammad Khatami, Ààrẹ ilẹ̀ Irani tẹ́lẹ̀
Àwọn aláìsí lóòní...
- [[]]
- 1902 – Émile Zola, olùkọ̀wé ará Fránsì (ib. 1840)