Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 5 Oṣù Kẹjọ
- 1583 - Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì sọ Erékùsù Newfoundland di ti ẹ̀, ó sì ṣèdásílẹ̀ lóníbiṣẹ ìlú St. John.
- 1962 - Ní Gúúsù Áfríkà asíwájú ìrìnkankan alòdì sí ìṣe ẹlẹ́yàmẹ̀yà (Apartheid), Nelson Mandela je sísọ sí ẹ̀wọ̀n. Wọn fií sílẹ̀ ní 1990, ó sì di Ààrẹ láìpẹ́.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1930 – Neil Armstrong, American pilot, engineer, and astronaut (al. 2012)
- 1962 – Patrick Ewing, Jamaican-American basketball player
- 1968 – Funkmaster Flex, American rapper, producer, and radio host
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1895 – Friedrich Engels, German philosopher (ib. 1820)
- 2001 – Otema Allimadi, Ugandan politician, Prime Minister of Uganda (ib. 1929)
- 2019 – Toni Morrison, olukowe ara Amerika (ib. 1931)