Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 9 Oṣù Kejìlá
Ọjọ́ 9 Oṣù Kejìlá: Ọjọ́ Ìlómìnira ni Tanzania (1961)
- 1872 – P. B. S. Pinchback bọ́ sí orí àga bíi Gómìnà ìpínlẹ̀ Louisiana, ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà àkọ́kọ́ tò dí gómìnà ìpínlẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà.
- 1961 – Tanganyika gba ìlómìnira látọwọ́ Brítánì.
- 1966 – Barbados di ọmọẹgbẹ́ U.N.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1608 – John Milton, akọewì ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì (al. 1674)
- 1842 – Peter Kropotkin, ánárkístì ará Rọ́síà (al. 1921)
- 1922 – Redd Foxx, aláwàdà ará Amẹ́ríkà (al. 1991)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1937 – Nils Gustaf Dalén, fìsíkístì ará Swídìn (ib. 1869)
- 1963 – D.O. Fagunwa, olùkọ̀wé ará Nàìjíríà (ib. 1903)
- 1971 – Ralph Bunche (Àwòrán), díplómátì ará Amẹ́ríkà (ib. 1904)
ojúewé yìí ti jẹ dídá àbò bò láti ṣàtúnṣe sí. See the protection policy and protection log for more details. Please discuss any changes on the talk page; you may submit an edit request to ask an administrator to make an edit if it is uncontroversial or supported by consensus. You may also request that this page be unprotected. |