Wikipedia:Ìtọrọ láti di alámòjútó/Ìforúkọsílẹ̀

Àkékúrús:
WP:RFA/I
WP:RFA/IFO
WP:RFA/ìforúkọsílẹ̀

Kí o tó forúkọsílẹ̀ tàbí fi orúkọ oníṣẹ́ míràn sílẹ̀ fún alábójútó, ó gbọ́dọ̀ kọ́kọ́ ṣẹ̀da ojú ewé fún ìforúkọsílẹ̀ oníṣẹ́ náà. Ó dára kí ó kọ́kọ́ wá oníṣẹ́ tí o fẹ́ fà kalẹ̀ kí o tó ṣẹ̀dá ojú ewé yìí, tí oníṣẹ́ náà bá fẹ́ dúró tàbí tí kò bá fẹ́ di alábójútó, ìṣẹ̀dá ojú ewé́ yìí lè jẹ́ ohun tí kò dára lójú wọn, fún ìdí èyí, kọ́kọ́ ṣàyẹ̀wò. Eleyí kò ní jẹ́ kí oníṣẹ́ náà kọ ìforúkọ rẹ̀ sílẹ̀

Ìtọ́sọ́nàÀtúnṣe

Lati fi orúkọ rẹ sílẹ̀Àtúnṣe

Lati fi orúkọ oníṣẹ́ míràn sílẹ̀Àtúnṣe

  1. Ṣe àrídájú ẹni tí o fẹ́ fi orúkọ rẹ̀ sílẹ̀. Eleyí kò ní jẹ́ kí ìtìjú wáyé látàrí tí wọ́n bá kọ̀ lati gba ìforúkọsílẹ̀ yìí.
  2. Ridájú wípé wọ́n pé òṣùwọn tí àwọn oníṣẹ Yorùbá Wikipedia ń fẹ́. Gbìyanjú kí o wo àwọn  RfA tí ó ti kọjá, kí o sì fi ẹni tí o fẹ́ fà sílẹ̀ wé àwọn tí ó yege àti àwọn tí kò yege.
  3. Nínú fọ́ọ̀mù tí ó wà ní ìsàlẹ̀ rọ́pò ohun tí wọ́n kọ síbẹ̀ tí ó ṣàfihan USERNAME pẹ̀lú orúkọ oníṣẹ́ tí o fẹ́ fà sílẹ̀ (wòó dáradáa kí o má ṣìí kọ). Fún ìdí kan, ti wọn kò ba kọ ohunkohun síbẹ̀, kọ, "Wikipedia:Ìtọrọ láti di alámòjútó/ONÍṢẸ́", rọ́pò "ONÍṢẸ́" pẹ̀lú orúkọ oníṣẹ́ náà .
  4.   TÍ ó bá ti gbé ẹ lọ sí ojú ewé míràn rọ́pò ÀPÈJÚWE ONÍṢẸ́  pẹ́lú ohun tí o fẹ́ kọ lorí oníṣẹ/ náà. Má ṣe rọ́pò OJÚ EWÉ ONÍṢẸ/ (tí kò bá ti ń ṣe wípé o fẹ́ fi orúkọ elòmíràn sílẹ̀)
  5. Tọ́jụ́ ojú ewé.
  6. Sọ fún oníṣe ní ọ̀rọ̀ oníṣé wípé o tí forúkọ wọn sílẹ̀ fún alabójútó nígbà tí o bá ti ṣẹ̀dá RFA yìí, tọ́ka sí ojú ewé tí o ṣẹ̀dá ("Wikipedia:Ìtọrọ láti di alámòjútó/ONÍṢẸ́", rọ́pò "ONÍṢẸ́" ).
  7. Dúró ki oníṣẹ́ náà gba ìforúkọsílẹ̀ yí kí ó sì dáhù àwọn ibéèrè tí ó wà níwájú rẹ̀ kí o tó fi RfA yìí sí Wikipedia:Ìtọrọ láti di alámòjútó/ONÍṢẸ́.
  8. Lọ sí ojú ewé yìí: Ṣe àtúnṣe sí ojú ewé yìí, kí o sì fi ojú ewé RfA rẹ ({{Wikipedia:Ìtọrọ láti di alámòjútó/Oníṣẹ̣́}}. rọ́pò Oníṣẹ́ pẹ̀lú orúkọ rẹ tàbí ẹni tí o fẹ́ fàsílẹ̀) sí abẹ́ "ètò ìdìbò"
    Bàyí, àwọn oníṣẹ́ á lè dìbò bí ó ti yẹ

Fún bí o ṣe lè ṣẹ̀dá ojú ewé ìforúkọsílẹ̀, wo Wikipedia:Ìtọrọ láti di alámòjútó/Àpẹrẹ. Tí ojú ewé àpérẹ yìí bá ti ṣí, fi orúkọ ẹní tí o bá fẹ́ jẹ́ kí o di alábójútó (yálà ara rẹ) rọ́pò "Àpẹrẹ" ní ibikíbi. Ṣe èyí ní abala fún adanwo rẹ (your sandbox). Ibẹ̀ ni kí o ti ko lọ sí ojú ewé ìforúkọsílẹ̀ rẹ (i.e copy the contents to your nomination subpage). Bí ojú ewé àpẹrẹ yìí ṣe rí ni ojú ewé ìforúkọsílẹ̀ rẹ ṣe gbọ́dọ̀ rí kí o tó fi RfA yìí sí Wikipedia:Ìtọrọ láti di alámòjútó.