Wikipedia:Ìtọrọ láti di alámòjútó/Oníṣẹ́
Ẹ kú déédé àsìkò yí o! Orúkọ oníṣẹ́ mi ni Agbalagba . Mo jẹ́ aláfikún sí Wikipedia èdè Yorùbá láti ǹkan bí ọdún mẹ́sàn án sẹ́yìn. Bákan náà ni mo sì jẹ́ Ààrẹ fún ẹgbẹ̀ Yorùbá Wikimedians User Group tí a ń ṣe agbátẹrù fùn Wikipedia èdè Yorùbá. Mo ti ṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ fún àìmọye ènìyàn nípa Wikipedia èdè Yorùbá. Mo ń tọrọ láti di alábòójútó fún Wikipedia èdè Yorùbá nítorí mo ṣàkíyèsí wípé a nílò alábòójútó si lòrì Wikipedia Yorùbá. Ẹ lè dìbò fúnminpẹ̀lú kí ẹ tẹ Mo faramọ nísàlẹ̀, kí ẹ sì kọ èrò yín síbẹ̀ pẹ̀lú. Ẹ ṣeun púpọ̀ fún ìbuwọ́lù yín.
Ẹ kú déédé àsìkò yí o! Orúkọ oníṣẹ́ mi ni Macdanpets. Mo jẹ́ aláfikún sí Wikipedia èdè Yorùbá láti ǹkan bí ọdún mẹ́fà sẹ́yìn. Bákan náà ni mo sì jẹ́ ọ̀kan lára ìgbìmọ̀ tàbí olùdarí ẹgbẹ̀ Yorùbá Wikimedians User Group tí a ń ṣe agbátẹrù fùn Wikipedia èdè Yorùbá. Mo ti ṣe ìdánilẹ́kọ̀ọ́ fún àìmọye ènìyàn nípa Wikipedia èdè Yorùbá. Mo ń tọrọ láti di alábòójútó fún Wikipedia èdè Yorùbá nítorí mo ṣàkíyèsí wípé a nílò alábòójútó si lòrì Wikipedia Yorùbá. Ẹ lè dìbò fúnminpẹ̀lú kí ẹ tẹ Mo faramọ nísàlẹ̀, kí ẹ sì kọ èrò yín síbẹ̀ pẹ̀lú. Ẹ ṣeun púpọ̀ fún ìbuwọ́lù yín.