Wikipedia:Àwọn alámùójútó
(Àtúnjúwe láti Wikipedia:Administrator)
Àwọn Alámójútó lè ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti pa ojú ewé kan rẹ́, dínà mọ́ àwọn bàsèjẹ́ kí wọ́n má lè ṣiṣẹ́ mọ́. Bí wọ́n bá sì dínà mọ́ ọ tí o sì fẹ́ kí wọ́n ṣínà tàbí gbà ọ́ wọlé padà, o lè kàn sí alámójútó tó dínà mọ́ ọ lórí ' ìkànì e meèlì rẹ̀ ' tí ó wà ní apá òsì ojú ewé oníṣẹ́ rẹ̀.
- Àwọn Alámójútó
- Demmy (láti 19 June 2010)
- Oníṣe:T Cells (láti 3 October 2019)
- Àwọn Alámùójútó tẹ́lẹ̀
- Freddie Mercury (láti 26 July 2006 sí 13 February 2008)
- Mark Dingemanse (láti 11 February 2006, ṣugbọn kìí ṣe alamojuto lórí yo.wikipedia mọ́).