Wikipedia:Ìwé-àlàyé àdàkọ

Àwọn àdàkọ jẹ́ ohun ìlò pàtàkì MediaWiki, sùgbọ́n wọ́n dojúrú fún ọ̀pọ̀ àwọn oníṣe tí wọn kò mọ iṣẹ́ wọn. Nítoríẹ̀ àwọn àdàkọ gbọdọ̀ ní ìwé-àlàyé tó ún ṣàlàyé iṣẹ́ wọn.