Wilhelm Conrad Röntgen tàbí Wilhelm Roentgen tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógbọ̀n oṣù kẹta ọdún 1845, tí ó sìn kú ní ọjọ́ kẹwàá oṣù kejì ọdún 1923 (27th March 1845 – 10 February 1923) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Jemani onímọ̀ físíìsì, tí ó ṣẹ̀dá àti àwárí iran oninagberingberin ninu awon iye igun iru a mo loni si x-ray tabi Röntgen rays lọ́dún 8 November 1895, tí oríire rẹ̀ sọ ọ́ di ẹni àkọ́kọ́ tó gba Ẹ̀bùn is Nobel nínú Físíìsì ni 1901.[1]:1

Wilhelm Röntgen
ÌbíWilhelm Conrad Röntgen
(1845-03-27)27 Oṣù Kẹta 1845
Lennep, Prussia
Aláìsí10 February 1923(1923-02-10) (ọmọ ọdún 77)
Munich, Germany
Ọmọ orílẹ̀-èdèGerman
PápáPhysics
Ilé-ẹ̀kọ́University of Strassburg
Hohenheim
University of Giessen
University of Würzburg
University of Munich
Ibi ẹ̀kọ́ETH Zurich
University of Zürich
Doctoral advisorAugust Kundt
Doctoral studentsHerman March
Abram Ioffe
Ernst Wagner
Ó gbajúmọ̀ fúnX-rays
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síNobel Prize in Physics (1901)

Àwọn Ìtọ́kasí ọ̀tọ̀

àtúnṣe
 
Wikiquote logo
Nínú Wikiquote a ó rí ọ̀rọ̀ tójẹmọ́:

Àdàkọ:Wikisource author

Àdàkọ:Nobel Prize in Physics Laureates 1901-1925

Àdàkọ:Authority control

  1. Novelline, Robert. Squire's Fundamentals of Radiology. Harvard University Press. 5th edition. 1997. ISBN 0-674-83339-2.

Ìkìlọ̀: Bọ́tìnì ìtò àkọ́kọ́ṣe "Röntgen, Wilhelm" dípò Bọ́tìnì ìtò àkọ́kọ́ṣe "Rontgen, Wilhelm" tẹ́lẹ̀.