Wilhelm Röntgen
(Àtúnjúwe láti Wilhelm Roentgen)
Wilhelm Conrad Röntgen tàbí Wilhelm Roentgen tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹtàdínlógbọ̀n oṣù kẹta ọdún 1845, tí ó sìn kú ní ọjọ́ kẹwàá oṣù kejì ọdún 1923 (27th March 1845 – 10 February 1923) jẹ́ ọmọ orílẹ̀-èdè Jemani onímọ̀ físíìsì, tí ó ṣẹ̀dá àti àwárí iran oninagberingberin ninu awon iye igun iru a mo loni si x-ray tabi Röntgen rays lọ́dún 8 November 1895, tí oríire rẹ̀ sọ ọ́ di ẹni àkọ́kọ́ tó gba Ẹ̀bùn is Nobel nínú Físíìsì ni 1901.[1]:1
Wilhelm Röntgen | |
---|---|
Ìbí | Wilhelm Conrad Röntgen 27 Oṣù Kẹta 1845 Lennep, Prussia |
Aláìsí | 10 February 1923 Munich, Germany | (ọmọ ọdún 77)
Ọmọ orílẹ̀-èdè | German |
Pápá | Physics |
Ilé-ẹ̀kọ́ | University of Strassburg Hohenheim University of Giessen University of Würzburg University of Munich |
Ibi ẹ̀kọ́ | ETH Zurich University of Zürich |
Doctoral advisor | August Kundt |
Doctoral students | Herman March Abram Ioffe Ernst Wagner |
Ó gbajúmọ̀ fún | X-rays |
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́sí | Nobel Prize in Physics (1901) |
Àwọn Ìtọ́kasí ọ̀tọ̀
àtúnṣeWikimedia Commons ní àwọn amóunmáwòrán bíbátan mọ́: Wilhelm Conrad Röntgen |
- Biography at the official Nobel site
- Annotated bibliography for Wilhelm Röntgen from the Alsos Digital Library Archived 2017-08-03 at the Wayback Machine.
- Wilhelm Conrad Röntgen Biography
- The Cathode Ray Tube site
- First X-ray Photogram
- The American Roentgen Ray Society
- Deutsches Röntgen-Museum (German Röntgen Museum, Remscheid-Lennep)
- Àdàkọ:Internet Archive author
- Àdàkọ:Librivox author
- Àdàkọ:Librivox author
- Röntgen Rays: Memoirs by Röntgen, Stokes, and J.J. Thomson (circa 1899)
- The New Marvel in Photography, an article on and interview with Röntgen, in McClure's magazine, Vol. 6, No. 5, April 1896, from Project Gutenberg
- Röntgen's 1895 article, on line and analyzed on BibNum Archived 2016-05-09 at the Wayback Machine. [click 'à télécharger' for English analysis]
- Open Library
- Àdàkọ:PM20
Itokasi
àtúnṣe- ↑ Novelline, Robert. Squire's Fundamentals of Radiology. Harvard University Press. 5th edition. 1997. ISBN 0-674-83339-2.
Ìkìlọ̀: Bọ́tìnì ìtò àkọ́kọ́ṣe "Röntgen, Wilhelm" dípò Bọ́tìnì ìtò àkọ́kọ́ṣe "Rontgen, Wilhelm" tẹ́lẹ̀.