William, Alade ti Wales

William, Alade ti Wales, (William Arthur Philip Louis; tí a bí 21 June 1982) ni ajogún gbangba si Itẹ Britani. Oun ni ọmọ agba ti Charles III ati Diana, Ọmọ-binrin ọba ti Wales.

Alade William
Alade ti Wales

Prince William in 2018
Spouse
Issue
Full name
William Arthur Philip Louis
House House of Windsor
Father Charles III
Mother Diana Spencer
Born 21 Oṣù Kẹfà 1982 (1982-06-21) (ọmọ ọdún 42)
Ile-iwosan St Mary, London, Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì
Religion Ìjọ ti Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì & Ìjọ ti Skọ́tlándì