William Kumuyi
Oludasile ati oludari ijo ijinle aye christiani
Olùṣọ́ àgùntàn William Folorunsho Kumuyi tí òpòlopò ènìyàn mò sí Pastor Kumuyi tàbí Oluso agutan Kumuyi ni olùdásílè àti alabojuto ìjo Deeper Life Bible Church gbogbo àgbáyé. William Kumuyi jé omo abínibí ìpínlè Osun ní orílè-èdè Nàìjíríà, abí William Kumuyi ní ìlú orunwa ìpínlè Ogun ní ojó kefa, osù kefa, odun 1941(6th June, 1941). A bí William Kumuyi sí ilé onigbagbo Kristieni ni ilu Orinle, wón si lo ilé-eko sekondiri ni ile-iwe Mayflower, léyìn igbana, wón ló ile ìwé giga tí Ìbàdàn láti keko gboye nínú imo mathematics. William Kumuyi ní iyawo (Esther Folashade Kumuyi) [1] ati omo méjì
William F. Kumuyi | |
---|---|
Olùṣọ́ àgùntàn W F Kumuyi pẹ̀lú ìyàwó rẹ̀ níbi ìsọjí àgbáyé tí ó wáyé ní Enugu | |
Olùdarí ìjọ Deeper Christian Life Ministry | |
Lọ́wọ́lọ́wọ́ | |
Ó gun orí àga 1973 | |
Asíwájú | Office established |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | William Folorunso Ikumuyiwa 6 Oṣù Kẹfà 1941 Erin-Ijesa, Ogun State, Protectorate of Nigeria |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Esther Folashade Kumuyi (m. 2010) |
Àwọn ọmọ |
|
Education | Mayflower School |
Alma mater | University of Ibadan (BSc) University of Lagos (PGCertEd) |
Occupation | |
Known for | Holiness movement |
Website | DCLM Website |
Àwon Ìtókasí
àtúnṣe- "Meet Pastor Kumuyi’s Second wife, she married @65 years". WISEPADI. 2020-05-29. Archived from the original on 2022-02-24. Retrieved 2022-02-24.
- ↑ "71 year-old General Superintendent of Deeper Christian Life Ministry, Pastor Williams Folorunsho Kumuyi, shocked and surprised nearly all his admirers a week ago. The Osun State born humble preacher married Esther Folashade Adenike Blaize at a secret ceremony in London, on Wednesday, October 13, 2010, exactly 18 months after Sister Abiodun Kumuyi, his wife, died.". Encomium Magazine. October 13, 2010. Retrieved October 12, 2022.