William Rashidi
aláápọn fún ẹgbẹ́ LGBT ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó tún gay
William Rashidi jẹ́ ajìjàngbara fún àwọn ọmọ egbẹ́ LGBTQ ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí wọ́n ń lọ́wọ́ nínú ìbálòpọ̀ láàrin akọ sí akọ àti abo sí abo. Ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ ìgbìmọ̀ tí ó ń darí ilé ṣiṣi fún ìlera àti àwọn ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn. Òun tún ni Olùdarí ti Equality Triangle Initiative, èyí tí ó fìdíkalẹ̀ sí Ipinle Delta, orílè-èdè Nàìjíríà.[1][2] Ó tún jẹ́ alágbàwí fún lilo Prophylaxis Pre-ifihan, (PReP) láti lè fi dènà ìkọlù àrùn HIV.[3] Ní ọdún 2011, ó ṣe ìlòdì sí ẹ̀wọ̀n ọdún mẹ́rìnlá fún ìgbéyàwó láàrin ọkùnrin sí okùnrin àti obìnrin sí obìnrin èyí tí àwọn ọmọ ẹgbẹ́ ilé aṣòfin àgbà orílẹ̀-èdè Nàìjíríà sọ di òfin. [4]
William Rashidi | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | William Rashidi |
Orílẹ̀-èdè | Ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà |
Iṣẹ́ | Human Rights Activist, and HIV Activist |
Gbajúmọ̀ fún | Human Rights Activism, LGBTIQ Advocacy, and Social Justice |
Title | Human Rights Activist |
Ẹ̀kọ́
àtúnṣeWilliam Rashidi kọ́ ẹ̀kọ́ gboyè jáde ni public policy láti ilé-èkó gíga Yunifásítì ti Queen Mary tí ó wà ní ìlú Londonu.
Àwọn Àtẹ̀jáde
àtúnṣe- A syndemic of psychosocial health problems is associated with increased HIV sexual risk among Nigerian gay, bisexual, and other men who have sex with men (GBMSM).
Àwọn ìtọ́kasí
àtúnṣe- ↑ "William Rashidi". AVAC. 2018-02-05. Retrieved 2021-09-14.
- ↑ "Williams Rashidi – Channels Television". Channels Television – The Latest News from Nigeria and Around the World. Retrieved 2021-09-14.
- ↑ "NGO Calls For Investment In New HIV Prevention, Treatment – The Whistler Nigeria". The Whistler Nigeria – Exclusive Stories, Breaking News, Government, Politics, Business. Retrieved 2021-09-14.
- ↑ "Nigerian gay man on country's hostility" (in en-GB). https://www.bbc.com/news/av/world-africa-16006716.