Winston Wole Soboyejo

ọmọ ẹgbẹ́ ọ̀mọ̀wé ìmọ̀ sáyẹ́nsí ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà

Winston Wole Soboyejo tí àwọn ènìyàn mọ̀ sí "Wole" jẹ́ onímọ̀ sáyẹ́ǹsì ti orílẹ̀-èdè America, tí àwọn òbí rẹ̀ sì jẹ́ ọmọ Yorùbá.[1] Ó ti ṣe ọ̀pọ̀lọpọl iṣẹ́ lórí ìmọ̀ sáyẹ́ǹsì.[2] Òun ni adele wọn ní Worcester Polytechnic Institute.[3]

Winston Wole Soboyejo
Soboyejo in 2008
Interim President of Worcester Polytechnic Institute
In office
May 16, 2022 – April 3, 2023
AsíwájúLaurie Leshin
Arọ́pòGrace Wang
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí1964 (ọmọ ọdún 59–60)
Palo Alto, California
Alma materKing's College London
Churchill College, Cambridge
Winston Wole Soboyejo
PápáMaterials science
Ilé-ẹ̀kọ́
Doctoral advisorJohn F. Knott

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Parker, Hilary (February 26, 2007). "Soboyejo tackles problems, inspires students". Princeton Weekly Bulletin (Princeton University) 96 (17). https://www.princeton.edu/pr/pwb/07/0226/1b.shtml. 
  2. "Provost WInston Soboyejo - Faculty profile". WPI (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-09-30. Retrieved 2021-09-30.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. "About the Provost". WPI (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-03-31.