Woody Allen (ibi Allen Stewart Konigsberg; December 1, 1935) je osere ati oludari filmu ara ile Amerika.

Woody Allen
Allen at the 2009 premiere of Whatever Works
ÌbíAllen Stewart Konigsberg
1 Oṣù Kejìlá 1935 (1935-12-01) (ọmọ ọdún 89)
Brooklyn, New York, U.S.
Iṣẹ́Actor
Director
Screenwriter
Comedian
Musician
Playwright
Awọn ọdún àgbéṣe1950–present
(Àwọn) ìyàwóHarlene Rosen (1954–1959)
Louise Lasser (1966–1969)
Soon-Yi Previn (1997–present)
Domestic partner(s)Mia Farrow (1980–1992)