Worknesh Degefa tí a bí ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n, oṣù kẹwàá, ọdún 1990 jẹ́ ọmọbìnrin tó ń kópa ní nú eré sísá ti ọ̀nà jínjìn ní orílẹ̀-èdè Ethopia.[1] Arábìnrin náà jẹ́ ẹlẹ́ẹ̀kẹrin nínú àwọn tó lè sá eré jù.

Worknesh Degefa
Worknesh Degefa near the halfway point of the 2019 Boston Marathon, which she won.
Òrọ̀ ẹni
Orúkọ kíkúnrẹ́rẹ́Worknesh Degefa
Ọjọ́ìbí28 Oṣù Kẹ̀wá 1990 (1990-10-28) (ọmọ ọdún 34)
Ethiopia
Sport
Orílẹ̀-èdè Ethiopia
Erẹ́ìdárayáSport of athletics
Event(s)Marathon, half marathon

Àṣeyọrí

àtúnṣe

Ní ọdún 2016, Worknesh kópa nínú Marathon ti ìdajì ti Prague, tó sì parí láàárín wákàtí 1:06:14[2]. Ní ọdún 2017, Degefa kópa nínu Marathon ti Dubai pẹ̀lú wákàtí 2:19:53. Ní oṣù January, ọdún 2019, Worknesh kópa nínú Marathon ti Dubai pẹ̀lú wákàtí 2:17:41[3]. Ní ọjọ́ karùnlélógún oṣù April, ọdún 2019, Degefa yege nínú Marathon ti Boston pẹ̀lú wákàtí 2:23:31[4].

Àwọn ìtọ́kasí

àtúnṣe
  1. Marathon Women
  2. Half Marathon
  3. 2019 Dubai Marathon
  4. Boston Marathon