Àjọ Ìlera Àgbáyé
(Àtúnjúwe láti World Health Organization)
Àjọ Ìlera Àgbáyé jẹ́ àjọ Àgbájọ àwọn Orílẹ̀-èdè Aṣòkan tí wọ́n dá sílẹ̀ fún ètò ìlera gbogbo àgbáyé. Wọ́n dáa sílẹ̀ ní Ọjọ́ keje Oṣù kẹrin Ọdún 1948, olú ilé iṣẹ́ rẹ̀ wà ní Geneva, Swítsàlandì.[1].[2]
![]() Àjọ Ìlera Àgbáyé | |
---|---|
![]() Àsíá Àjọ Ìlera Àgbáyé | |
Irú | ẹ̀ka Àjọ àwọn Orílẹ̀-èdè |
Orúkọkúkúrú | WHO OMS |
Olórí | Margaret Chan, Alákóso |
Ipò | Active |
Dídásílẹ̀ | Oṣù Kẹrin 7, 1948 |
Ibùjókòó | Geneva, Swítsàlandì |
Ibiìtakùn | who.int |
Òbí | United Nations Economic and Social Council (ECOSOC) |
Àwọn ìtọ́kasíÀtúnṣe
- ↑ "World Health Organization". The British Medical Journal (BMJ Publishing Group) 2 (4570): 302–303. 7 August 1948. doi:10.1136/bmj.2.4570.302. JSTOR 25364565.
- ↑ Sze Szeming Papers, 1945–2014, UA.90.F14.1, University Archives, Archives Service Center, University of Pittsburgh.