Woyo

Woyo

Ní agbègbè Congo (Zaire) ni a tin í àwọn ẹ̀yàn Woyo. A kò le sọ pàtó iye àwọn tó ń gbé agbègbè yìí. Kiwoyo (Bantu) ni èdè àwọn ẹ̀yà yìí. Solongo, Kongo, Vili àti Yombe jẹ́ àwọn Olùbágbé. Ní ñǹkan ẹgbẹ̀rún ọdún kẹ̀ẹdógún (prior 15th century) ìtàn se akọ̀sílẹ rẹ pe ọmọọba bìnrin Nwe kò àwọn ènìyàn rẹ tọ́ yẹ kan dí Woyo sodí lo sí ojù gbangba níbi tí wọ́n gbé wà bayìí. A pa ìlu wọn àkọ́kọ́ run nígbà tí Ọba Kikongo tó jẹ́ olùbágbè wọn Kógun jàwọ́n. Arábìnrìn Kongo la gbọ́ pó dá ilú Woyo kejì silẹ̀. Isẹ́ àgbẹ̀de adẹ́mu apẹja ati ode jẹ́ àwọn isẹ́ ọkùnrin Woyo